Unintentional Lyrics
- Genre:Hip Hop & Rap
- Year of Release:2024
Lyrics
Unintentional - Baby De Scarface
...
O ti mi lu lẹ
Mo ya sa dide
Uhh
Emi lo fẹ ba ṣeṣekuṣe
Emi ti mo gbon
Mo ya pick race
Ti mo tun wa sabi sabi the level
Omo to tun wa je wi pe soldier ni dad eh
T on ba lọ mu mi ni ibiti mo ti n kẹ
Tọ n ba mumi
Tọ n ba na mi
Tọ n ba ṣami
Tọn ba run mi
Ton ba ge mi
Buh o pada l'awon time kan
Mi o mọọmọ
Mo lọ le wọn lọ san gangan
Koda mo jẹ noodles
Mo tun mu golden morn
O ni bby are you okay?
Mo ni mo fine gan
O ni ṣoyo?
Mo ni mo yo pa
O ni oya jẹ ka bẹrẹ lori sofa
But gbogbo kini yen emi o mọọmọ o
Ahh, mi o mọọmọ o
Mi o mo n kankan
Mi o mọọmọ o
Mi o mọọ mọ o
Gbogbo kini yen emi o mọọmọ o
Ahh, mi o mọọmọ o
Mi o mo n kankan
Mi o mọọ mọ o
Mi o mọọmọ o
Buh later later in the night
Logonjo oru
Mo need lati pada jade bi ole loru
Like a Thief in the night
I went to her room window
And i called her name
Mo ni bby konji ma lo mu mi
O ni eh ki lawa fun rawa fun
Joko s'ori bi na
Ki n fun e ni
Babanlaku Mother baba fucking head
Ahh Emi naa ba joko mo ba feyin ti
Bi ẹni to n j'ounje ọmọ at 70
Nkan to n gbenu mi is a deity
Tori tokan mi se balẹ is amazing
Nile soldier
To ni baba sakabula
To ni german Shepard
Nibo ni mo fe gba
T'aja yin ba decide lati fi mi se dinner
Uhhh buh mi o phor
Mo tun fi energy si ni
Ni gba ti mo run mo corner kan
Nibi ton gbe fan si
O ni ahhh
My baby
Mi o mọ po sabi toyi
O ni Balthasar gan ko se to iwo bobo yi
Ase gbogbo jesu jesu bby yi
Ko muna doko to
Tori mi o mọ pole d'oko
Bo shey feran jesu to
Oni poran ina
Olowo ina
Bo shey n yin mi niyen
Nigba to je doggy tan
But gbogbo kini yen emi o mọọmọ o
Ahh, mi o mọọmọ o
Mi o mo n kankan
Mi o mọọmọ o
Mi o mọọ mọ o
Gbogbo kini yen emi o mọọmọ o
Ahh, mi o mọọmọ o
Mi o mo n kankan
Mi o mọọ mọ o
Mi o mọọmọ o
(Oni poran ina
Olowo ina
Oni poran idan
Olowo idan
Oni poran ina
Olowo ina
Oni poran idan
Olowo idan)