![Senwele Special](https://source.boomplaymusic.com/group2/M00/08/98/rBEeNFgHWoyAeUe1AADUvdgaI24535.jpg)
Senwele Special Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2010
Lyrics
Senwele Special - Evang. Bukola Akinade
...
(Beat)x3
Ebami dupe o
Ebami dupe
Eyan to mo riri Jehovah
Ebami dupe
Fiyin fun, kabiyesi ologo didan
Fiyin fun oba to gbe yi fun ole
E ba wa dupe
Fiyin fun, kabiyesi Ologo didan
Fiyin fun oba to gbe yi fun ole
E ba wa dupe