![My Hymn For Him](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/02/07/1ef77bd61d1a4b57a093ac211da34c1c_464_464.jpg)
My Hymn For Him Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2022
Lyrics
My Hymn For Him - Evang. Bukola Akinade Senwele Jesu
...
ile miran iyanrin ni mo duro le kristi apata ile miran iyanrin ni majemu ati eje re lemi o ro mo bikun mi de gbati ko salatiletin mo o je ireti nla fun mi mo dure le kristi apata ile miran iyanrin ni mo duro le kristi apata ile miran iyanrin ni bipe ikeyinba si dun A n ba le wa ninu Jesu ki n wo ododo re nikan kin duro niwaju ite mo duro le kristi apata ile miran iyanrin ni 2x