Fadura Korin Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2013
Lyrics
Fadura Korin - Evang. Bukola Akinade
...
Mo de si O l'orun o, f'aanu ba mi se e!
Mo de si O l'orun o, f'aanu ba mi we o!
Mo de si O l'orun o, f'aanu yanju pro mi, Baba o, k'oju ma to mi o o e e!
Agbara Emi Mimo w'onu aye mi ko wa se 'yanu
Ohun kan ha was t'Olorun ko le se? (3x)
Ohun gbogbo o, sise in f'Oluwa!
....