![Senwele](https://source.boomplaymusic.com/group2/M0C/7A/25/rBEeqF2ZFlmAeDtiAAD3TFIffV0554.jpg)
Senwele Lyrics
- Genre:Holiday
- Year of Release:2014
Lyrics
Senwele - Evang. Bukola Akinade Senwele Jesu
...
ope ni n oo shey n o ni sharoye o
ope ni n oo shey n o ni sharoye o
aroye eshi ki lo yo o le fayee wa
aroye eshi ki lo yoo le fayee waa
ope ni n o shey n o ni sharoye o
Tewo gbope mi Oba iseda o
Tewo gbope mi Oba iseda o
ete mi gbayin enu mi gbope
emi gbe O ga
ete mi gbayin enu mi gbope
emi gbe O ga
Oya eje a gbe ga
eje a gbeee ga
eyan to mo riri Re
oya eje a gbee ga
Olorun nlaaa oooo
orule to bori ode agbaye
mori mori to mori gbogbo wa
awolule bi ateeleke
oya eje a korin
eje a korin
eyan to ronu jinle
ko jade wa korin
Kabiyesii Re