![Olorun Lolebun/Bayebanyeni](https://source.boomplaymusic.com/group1/M00/01/2A/rBEeMlfx8wqAdKBHAAB2obJ5JLk202.jpg)
Olorun Lolebun/Bayebanyeni Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2007
Lyrics
[ti:05 Olorun Lolebun-Bayebanyeni]
Ori ma mo jen mo iyi ara mi
Ori mi ma ma je o
Eda mi ma ma je o
Ori ma mo jen mo iyi ara mi oo
Ori mi ma ma je o
Eda mi ma ma je o
Eda mi ma ma jen jo ara mi loju o e (x2)
Shebi ire ni
Shebi ire lo pemi o
Shebi ire lo yan mi o
Ore ofe nla
Ore ofe nla ni (x2)
Ijinle niyi o ob aataye ro
Ila jora leju ila ko
Iko yi jora re loju iko yi wo ewu eje o
Nebuchanezari lo jora re loju lo deni nba ebora jeun no
Ori ma mo je o
Eda mi ma ma je o
Ori ma mo je o
Eda mi ma ma je o
Ori mi ma ma jen jo ara mi loju o e
Ori ma mo jen mo iyi ara mi
Ori mi ma ma je o
Eda mi ma ma je o
Ori ma mo jen mo iyi ara mi oo
Ori mi ma ma je o
Eda mi ma ma je o
Ori mi ma ma jen jo ara mi loju o e
Tani ologbon oun t’olorun o mo si
Tani oni mo oun t’olorun o mo si
Ara kile wi no
Tani ologbon oun t’olorun o mo si
Tani oni mo oun t’olorun o mo si
Olorun llon fun ni logbon
Olorun ni nfi ogbon jogun fun ni
Baba mi ni
Baba mi ni nfi imo jogun fun yan
Olorun ni nfi ogbon jogun fun ni
Baba mi ni nfi imo jogun fun yan
Alawura bi o dakun fun mi logbon kun ogbon
Alawura bi o dakun fun mi ni imo kun imo
Oluwa lo lebun
Oluwa lo le gba
Oluwa lo mono to fe kolo si (x2)
Baba lo fi fun o ore mi ko lo
Baba lo fi fun o ore mi ko lo
Boya loni boje lola koma seni to mo
Baba yio pe o lojo kan kowa jinyin
Oluwa lo lebun
Oluwa lo le gba
Oluwa lo mono to fe kolo si
Ebun ke ebun tolorun fun wa ka lo fun ogo olorun
Ebun ke ebun ti baba fun wa ka lo fun ogo re
Pelu igberaga ko
Pelu ijora eniloju ko
Toripe olorun lo fun ni
Olorun losi le gba
Ba ba lo bob a ti fe
Oba to gba egbon lowo esau to gbe fun jacobu
Talo fe sope ko se da
Ati ri akorin to tin yin baba ti kole yin baba mo
Ati oji se to tin jise baba tio le jise mo
Ati ri oun elo olorun nigba kan to ti di ohun elo alo pati o
E o ori mi ma ma je o
Eda mi ma ma je o
Ori ma ma je o
Eda mi ma ma je o
Ori mi ma ma jen jo ara mi loju o e
Oluwa lo lebun
Oluwa lo le gba
Oluwa lo mono to fe kolo si (x2)
Baba lo fi fun o ore mi ko lo
Baba lo fi fun o ore mi ko lo
Boya loni boje lola koma seni to mo
Baba yio pe o lojo kan kowa jinyin (x3)