![Alagbara](https://source.boomplaymusic.com/group1/M00/01/2A/rBEeMlfx8wqAdKBHAAB2obJ5JLk202.jpg)
Alagbara Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2007
Lyrics
[ti:04 Alagbara]
Olorun olodumare
Awa fiyin fope fun o
Ki ahan wa korin iyin
Ki imisi orun so kale
Eyin malaika tin korin yin baba
Kerubu seraph e sokale wa
Seri ma lori esokale wa
Ki imisi orun sokale
Olorun olodumare
Kooooo
Awa fiyin fope fun o
Kooooo
Ki ahan wa korin iyin
Ki imisi orun sokale
Alagbara iwo ni ka ma yin
Ijinle ife agbara re ga o o
Iwo to pa wa mo ninu iji aye yi
Ogo iyin lo ye o baba
Jehovah jireh olupese wa
Alpha omega ibere ati opin
Iwo to pa wa mo ninu iji aye yi
Ogo iyin lo ye o baba
Alagbara iwo ni ka ma yin
Ijinle ife agbara re ga o o
Iwo to pa wa mo ninu iji aye yi
Ogo iyin lo ye o baba
Towo koto ti ota gbe
Towo iran ti aye di
Odi koto pa lofo
Otun ino wo ka
Iwo ni ka ma yin
Iw ni ka ma yin
Alagbara iwo ni ka ma yin
Ijinle ife agbara re ga o o
Iwo to pa wa mo ninu iji aye yi
Ogo iyin lo ye o baba
Nigba t’aye bere wipe tal’olorun wa
Taye rope iwo koni le gbani mo
Iwo ran iranlowo re lati orun wa tosi gbani lowo won (x2)
Alagbara iwo ni ka ma yin
Ijinle ife agbara re ga o o
Iwo to pa wa mo ninu iji aye yi
Ogo iyin lo ye o baba
Nigba t’aye bere wipe tal’olorun wa
Taye rope iwo koni le gbani mo
Iwo ran iranlowo re lati orun wa tosi gbani lowo won (x2)
Alagbara iwo ni ka ma yin
Ijinle ife agbara re ga o o
Iwo to pa wa mo ninu iji aye yi
Ogo iyin lo ye o baba
Nigba t’aye bere wipe tal’olorun wa
Taye rope iwo koni le gbani mo
Iwo ran iranlowo re lati orun wa tosi gbani lowo won (x2)
Alagbara iwo ni ka ma yin
Ijinle ife agbara re ga o o
Iwo to pa wa mo ninu iji aye yi
Ogo iyin lo ye o baba (x2)