![Mo Ti Gbekele Jesu](https://source.boomplaymusic.com/group1/M00/01/2A/rBEeMlfx8wqAdKBHAAB2obJ5JLk202.jpg)
Mo Ti Gbekele Jesu Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2007
Lyrics
[ti:03 Mo ti gbekele Jesu]
Mo ti gb’okan le jesu alagbara
Orisun ayo ti ki d’oju tini
Mo ti gb’okan le jesu alagbara
Orisun ayo ti ki d’oju tini
Oba tin sh’ore fun ni layi ni sinregun
Atoni gba ti ki gba abetele o
Ayo mi
Ayo mi
Ayo mi o
Jesu l’ayo mi
B’aye ban bere pe olorun mi da o
B’ota ban bere pe olorun mi da o
Jesu ti mo mo o koni doju ti mi (x2)
Agbara re gaju t’aye lo
Agbara re gaju t’esu lo
Baba mimo jewo agbara re
Agbara re gaju t’aye lo
Agbara re gaju t’esu lo
Baba mimo jewo agbara re
Gbogbo ipa ati agbara
Gbogbo ogbon ati imo gbogbo o
Baba mimo jewo agbara re
Gbogbo ipa ati agbara
Gbogbo ogbon ati imo gbogbo o
Baba mimo jewo agbara re
Ire mon wa mo gbe ire mi bowa o
Ire ma wa
Ire ma bo
Ire tete wa file mi joko si o
Ire ma bo
Ire mon wa mo gbe ire mi bowa o
Ire ma wa
Ire ma bo
Ire tete wa file mi joko si o
Ire ma bo