![Testimony](https://source.boomplaymusic.com/group1/M00/01/2A/rBEeMVfx8x2AMFBIAAB20qL3-LY090.jpg)
Testimony Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2009
Lyrics
[ti:05 Testimony]
Ara mi okan mi soji o
Emi o so fun yin
Emi fe so fun yin o
Ore ofe nla ti jesu oluwa wa
Dide ko so fun wa
Dide ko so fun wa
Ore ofe nla
Ore ofe nla
Ore ofe nla ti jesu kristi
Dide ko so fun wa
A fe gbo
Lekan mo shako lo sinu iparun aye
Jesu wami ri
Owa ra mi pada
Otun so mi domo
Shebi oye kin so fun yin
Dide ko so fun wa
Dide ko so fun wa
Ore ofe nla
Ore ofe nla
Ore ofe nla ti jesu kristi
Dide ko so fun wa
Ninu ipanju mori iranwo re
Lekan mo foju
Sha wo mo riran
Lekan mo ya aro
Sha wo mole rin
Lekan ahan mi lo
Ako lolo sha lemi
Wo emi ni mo nfo hun o
Sehbi oye kin so ke gbo
Dide ko so fun wa
Dide ko so fun wa
Ore ofe nla
Ore ofe nla
Ore ofe nla ti jesu kristi
Dide ko so fun wa
Aje ti ri mi won wo tan ti fe ma yan mi je
Olorun lo gba ela mi lowo won
O wa so mi dalaye pada o
Ofi emi iye sinu mi
Sugbon o ye kin so kegbo
Dide ko so fun wa
Dide ko so fun wa
Ore ofe nla
Ore ofe nla
Ore ofe nla ti jesu kristi
Dide ko so fun wa
Olore ofe nla
Baba olore ofe nla
Baba olore ofe nla o
Awa yio royin
Awa yio royin ore to se
Oruko wo lodun lenu mi
Oruko jesu ni
Oruko wo lodun ju oyin lo
Oruko jesu ni (x2)
Oruko t’aje gbo to salo o
Oruko to so osho ile di alayi l’agbara
Oruko to nja ni ide
Oruko to ntu ni igbekun
Oruko baba oruko nla
Oruko wo lodun lenu mi
Oruko jesu ni
Oruko wo lodun ju oyin lo
Oruko jesu ni (x2)
Oruko temi ni lai gbe ebo s’orita
Oruko temi pe nigbataye npofo o
Oruko tofo feya
Oruko to mu won bale
Oruko jesu ni
Oruko wo lodun lenu mi
Oruko jesu ni
Oruko wo lodun ju oyin lo
Oruko jesu ni (x2)
Oruko jesu yi o
Oju gbogbo oruko
Oruko yi o
O le bogun aye pa
Oruko jesu yi o
Lo le fun o layo
Oruko ni
Kilo oruko re
Oruko jesu ni
Ntan egan eni
Oruko jesu ni
O ma nwo ogbe eni san
Oruko jesu
O le eru lo
Oruko jesu ni
Manner la koko tebi npa
Oruko jesu
Sawo orije iye
Oruko jesu ni
Apata ti mo duro le
Oruko jesu ni
Ibi isadi mi
Oruko jesu
Ile isho abo mi
Oruko jesu ni
To kun fun ore ofe nla
Oruko jesu ni
Ipinle ireti mi
Oruko mi
Orisun ayo mi ni
Oruko jeseu ni
Olugbala ara aye
Oruko jesu ni