- Genre:Holiday
- Year of Release:2018
Lyrics
Oriki - Tim Godfrey
...
kabiyesi atoperi eledumare ni se
kabiyesi agbanla atoperi eledumare ni se
baba mi awimayewu
baba mi awilese
baba mi aselewi
baba mi oba nla tin gbani lojo isoro
eletigboun maroye
abeti nukara bi ajere
erujeje leti okunkunpa
oba to teile bi eni teni
ota somo bi eni taso
idile jese to ko le ku lai
eyin loba to see oungbogbo Lori ite
ina agbada
ina aseda
ina apeda(*2)
ogbagba tin gabni
alagbada ino
alawotele orun
alarigbedegbede bi enilari
edumare moti mu ope mi wa fun eni to pe ye fun moti finyi fun eni to iyin se tere
eni to se mimo
ton je mimo
ton mu mimo
ton gbe ibi mimo
ton ni wa mimo
alade ogo
talaba fi o we
lion of Judah (*2)
ayo to ni Lola
ope ye o o baba
edumare gbo pe wa
tire ni o(*2)
mofisile fun o
owuro mi osan mi ale mi oo
tire ni oluwa(all *2 from tire ni oluwa)
my paise belongs to you(*2)
ese adupe oo(*4)
igwe (*6)