Agesinkole ft. Adam Songbird Lyrics
- Genre:Alternative
- Year of Release:2022
Lyrics
Agesinkole ft. Adam Songbird - ANTHILL MUSIC
...
Eemo re o...ooo
(Ahuuuuu)
Digbolugi wolu.
(Ahuuuu)
Taja ba bunije kii soogan
(Ahuuuu)
Ta leni to gbena woju ekun
(Ahuuuuu)
Ta le ní to fowo ta Ku laya
(Ahuuuuu)
Kolomo towo Omo re bonu Aso
Kolomo(Ahuuuuu ) kilo fomo re (Ahuuuuu )
Yan Kan yankan ní Kankan ke ní sale odo(Ahuuuuu )
Oro o Oro o lesisin ke lowo idan re (Ahuuuuu)
Ageshinkole faraya... Ageshinkole fakekori
Ageshinkole bugije... Ageshinkole Tuto spoke o...o foju gbaaaa
E eeeee, e funra ooode.... Ageshinkole wolu de oooo.
O deeeee o. Ageshinkole wolu de.
o o deeee oooo Ageshinkole wolu de oooo.
O deeeee Digbolugi wolu de .
Ageshinkole faraya, Ageshinkole fakekori ...
Ageshinkole bugijeeeeeee ooooo.