OKETE ft. Adam Songbird & Ojopagogo Lyrics
- Genre:Soundtrack
- Year of Release:2023
Lyrics
OKETE ft. Adam Songbird & Ojopagogo - ANTHILL MUSIC
...
intro
ore ni mo se ooooo ×2
sound
yeeeh, ore eeeeeee
eeyan lon kuku she onidajo, olorun oba o dawo ise duro.
be dajo, bee dajo, olorun oba temi ju'yan lo
yeeeh
ore ni mo se ooooo ×2
o wa pada di bi mo mi lowo ooo
eeeee akogun gbera, gbera nle ko dide
irin aremabo to rin yii, yio leyin o
oke to gun yii ti jabo
chorus:
okete, ase bayii ni wa re ×2
o ba ’fa mule, o da fa ×2
okete eeee ×2
bayii niwa re eee
eeyan lon kuku she onidajo, olorun oba o dawo ise duro
be dajo, bee dajo, olorun oba temi ju'yan lo
ore ni mo se ooooo ×2
won ni omo eni ku san ju omo eni sonu lo o
ewo wa ni k'omo eni ku sonu