ADARALEWA ft. Dhortune & Tolu Obanro Lyrics
- Genre:Soundtrack
- Year of Release:2024
Lyrics
ADARALEWA ft. Dhortune & Tolu Obanro - ANTHILL MUSIC
...
Beat…..
Oju to regun to roro tio ri gelede oju naa oma ti ma ri nkan nkan oooo.
Oju naa oma ti ri’n kan kan oooo. Ko ri ‘ n kan kan…..
Adaralewa mi o, omo to niwa ni ooo
Iwa sha lewa mi oo
Eba’n kewa mi oo, odoo do ifewa oni re danuu lai lai koni ree danuu ooooo.
Apon bė po re o. Mofe ko magbe o si o
Ifemi ole yipada ra ra o.
Baye fe baye ko se o, beere kan to’n mi mi o ni je ra ra ra o.
Bo San doruu, boruu dó San.. oooo
Ifemi si ő, koni ree danuu.
Boo jo roo bi’n na joo ko sohun ti o yawa oo.
Iwo nikan, iwo nikan, iwo nikan lee ni okan mi yan oo.. iwa lewa mi awe lewa, Apon bė po re Adaralewa mi ooo…
Iwo lokan mi yan layoo.
Apon bė po re o, Mofe ko magbe o si o,
Ifemi ole yipada ra ra o.
Baye fe baye ko se o, beere kan to’n mi mi o ni je ra ra ra o.
Bo San doruu, boruu dó San.. oooo
Ifemi si ő, koni ree danuu.…….