Ife Mi Lyrics
- Genre:Pop
- Year of Release:2021
Lyrics
Omo Olorunlogbon
O npa mi bi oti
Ade mofe s'oro Ife
E je nso
O ti ngbe mi l'okan tipe
Onitemi, ife mi my dear
B'ose nse mi
Baby mi o leso
W'oju ojo
Weather for two baby
Egbe ile yin
Is for me and mine nikan
Kose fi mora
Dakun je n sign in baby
Mole tori e
Kingb'oga soldier leti
Koye mi to
There's something about you baby
To npa mi bi oti
Olo mi s'alaye
B'oje t'owo
Olohun lo l'aranse
Mo ntepa mose
Baba ti ni n mama s'ole
Olo mi o eee, Ife mi o eee
Ayanfe mi o eee, Ife mi o eee
Olo mi o eee, Ife mi o eee
Ayanfe mi o eee, Ife mi o eee
Yah Allahu mi
Mo nfi yah yase kun Ade
Psalm 23
Ni mo fi n s'adura Ade
Isaja meje
Mo fi de adura mi l'ade
B'oje torin
Universal musician l'Ade
T'o ba Obey mi
Ma ko'rin fun e bi
Sunny Ade
Abi Agbajelola
Mr Fuji Ayinde
Ade ori e ni
T'anybody ole de
When the going was rough
Ko seni to momi Ade
Afi iwo nikan
A l'Ade owo si made
Amo'le ti kun
Dakun ma gba bagi Ade
Olo mi o eee, Ife mi o eee
Ayanfe mi o eee, Ife mi o eee
Olo mi o eee, Ife mi o eee
Ayanfe mi o eee, Ife mi o eee
Oro ife le pupo ewen 'rabe
T'aba nfe 'losiwaju o
Oye k'afi ife han sirawa
Gbogbo nkan l'aye
K'ato ro'nu ile
K'ato ro'nu omo
K'ato ro'nu owo o
Oye k'amo pe ife losiwaju
Iwe mimo ni
F'eni 'keji re
Gege bi ara re o
L'ose ye k'afi ife lo
K'aye le roju uu
Olo mi o eee, Ife mi o eee
Ayanfe mi o eee, Ife mi o eee
Olo mi o eee, Ife mi o eee
Ayanfe mi o eee, Ife mi o eee