![Ore Olorun](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/06/23/e5a0b880172142aaa04dab4a1719049a_464_464.jpg)
Ore Olorun Lyrics
- Genre:Pop
- Year of Release:2021
Lyrics
Omo Olorunlogbon
T'Olohun ba s'ore
T'o lero lojiji
Oye keyan dupe
K'ore ohun le gba'lekun
Jehovah lo s'ore
Ti nlero lojiji
Emi naa a dupe
K'ore ohun le ma'lekun
Oba to nri wa, t'enikan ori
Oba to ngbo wa, t'enikan ogbo
Owun lomo wa
Owun lomo wa
Owun kan naa lomo'wa wa
Ko l'ebi
Ko l'ara
Ko l'orogun
Ko l'obakan
Oba ti o l'alabagbe
Kobi'mo
Eni kan obi
Owun ni ibere
Owun l'aarin
Owun kan naa tun l'opin
Alpha and Omega Baba
Gbogbo nkan lomatan
Owun nikan ni o ku ti o nitan
T'Olohun ba s'ore
T'o lero lojiji
Oye keyan dupe
K'ore ohun le gba'lekun
Jehovah lo s'ore
Ti nlero lojiji
Emi naa a dupe
K'ore ohun le ma'lekun
Oba ti o d'eni ti o le pa
Kod'eni ti o le mu
Amuni
Agbani
Apani
Ajini
Kabie osi Olohun mi
Abeti lu kara bi ajere
Eleti gbaroye, t'o ngbo gbogbo aye pata
T'afefe
T'eranko
T'eyan
Pel'awon alijonu t'oda
Gbani gbani ti gbogbo aye nsa ba
Oluso ode orun
Laini security kankan
T'otun nso gbogbo aye pata
Lojo kan
Niseju kan
Lasiko kan
Alabe'nu a nsa siiiii
Loooojooosorooooooo
T'Olohun ba s'ore
T'o lero lojiji
Oye keyan dupe
K'ore ohun le gba'lekun
Jehovah lo s'ore
Ti nlero lojiji
Emi naa a dupe
K'ore ohun le ma'lekun
Oba Ajidara
T'o d'eni t'o ndara
T'o d'eni t'o nronu ara t'o fe da
T'o d'eni ti o ni le r'ara da rara
T'o da t'ebi t'ara pel'ara t'on fe da
Oba to da asebi
Pel'ara ti o da to nda
T'o d'enire
Pel'ara t'oda to nda
Eni t'ogbon o da gbon
Eni go naa o da go Akanda
T'Olohun ba s'eda lona, kil'ogbon
Modupe, o fi mi da'ra tio da Olohun
Motun ndupe
Modupe
Modupe ooo
Modupe
P'ara mi o gbe'nu mi Akanda