Kayamata Lyrics
- Genre:Pop
- Year of Release:2021
Lyrics
Awon omo kayamata
Mr Bachelor ma baase lo
Roora
Firo gbaro boda alacada
Roora
Sugar coated, won lenu yin dun gan
Roora
O fe mu t'oju e kuro ni
Roora
Ko tie dun, a sun bi ere
Roora
Obirin meta n'iwo nikan
Roora
A ni meta-mata loma ndun gan
Roora
K'eyan setan fi 33 le
Roora
A mu'ti yo a l'owun nsaye
Roora
O s'aye, aye lonse e
Roora
Boda alacada, dikan mu
Kojo to lo tan o
Ko ma pada lo ko s'owoo
Awon omo kayamata
Nibi loma kusi
LORI IRO
Waa di Mario
Boya loma dele
Toba lo ko sowo
Nibi loma kusi
Awon omo kayamata
Boya loma dele
Baby yi m'ere se
Nibi loma kusi
Awon omo kayamata
Boya loma dele
Daddy oni kini sugar
Roora
Bose ngbe dudu, l'ongbe pupa
Roora
Kosi underage loju yin
Roora
T'oba ti ya l'oma gbe'ro de
Roora
I was very busy n'ibi ise
Lago mefa la siwo
O re mi ju my dear
Bi nse nbo lona Darling
Tanker kan ma lo subu
O jo pe epo logbe
Maa gbegbe e koja
I'm missing you Baby
Ki nsa le tete de'le
Iyawo a wa da lohun
Honey, ewa bi toda lodge si Daddy
T'o ba di l'ola ke wale
L'eni t'oti lodge tipe
Uncle aturota rora
Aanu e lose mi o
K'o ma pada lo ko sowo
Awon omo kayamata
Nibi loma kusi
LORI IRO
Waa di Mario
Boya loma dele
Toba lo ko sowo
Nibi loma kusi
Awon omo kayamata
Boya loma dele
Baby yi m'ere se
Nibi loma kusi
Awon omo kayamata
Boya loma dele
Kosi 'bi ti kii dun lara eran
Oni ibi ti kaluku ma nferan ni
T'oba lonje nle
Dakun ma daka je mo
B'o lonje nle
Ore mi so buka jeun
Onje ori titi
Egbo sole dabi ile
Epo black market
Loma nba carburator je
Ojogbon eyan to ngbo mi, ikilo ni
Ma so p'ogbo
Dakun bami foyegbe
Ore jawo nbe
K'o ma pada lo ko s'owo
Awon omo kayamata
Nibi loma kusi
LORI IRO
Waa di Mario
Boya loma dele
Toba lo ko sowo
Nibi loma kusi
Awon omo kayamata
Boya loma dele
Baby yi m'ere se
Nibi loma kusi
Awon omo kayamata
Boya loma dele