Ore Wa Wo Jesu Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2001
Lyrics
Ore wa wo jesu
Gbogbo ohun aye yi
Asan ninu asan
Omule mofo laye
Gbe oju re soke
Ko wa wo jesu to fe o
Yo gba ola laye
Yo mu o wole ogo
Ore wa wo jesu
Gbogbo ohun aye yi
Asan ninu asan
Omule mofo laye
Gbe oju re soke
Ko wa wo jesu to fe o
Yo gba ola laye
Yo mu o wole ogo
Sowo niwo fe ni
Tabi omo lo fe bi
Eyi to wu ko je
Sha gboju re si jesu
Oun ni eleda re
O mo oun to fe oh
Yo se oun to fe
Yo mu o wole ogo
Ore wa wo jesu
Gbogbo ohun aye yi
Asan ninu asan
Omule mofo laye
Gbe oju re soke
Ko wa wo jesu to fe o
Yo gba ola laye
Yo mu o wole ogo
Kilo n ja o laya
Kini ibanuje re
Sha gboju re soke
Lati wo eleda re
Yi o gbe o soke
Wo yo si ri ogo re
Yi o da o lare
Yo mu o wole ogo
Ore wa wo jesu
Gbogbo ohun aye yi
Asan ninu asan
Omule mofo laye
Gbe oju re soke
Ko wa wo jesu to fe o
Yo gba ola laye
Yo mu o wole ogo
Se ile re ko gun ni
Tabi ona re ko ye o
Jesu lona iye
Mase da ona miran
Ona miran le kuna
Sugbon jesu ko je kuna
Yo mu ona re gun
Yo mu o wole ogo
Ore wa wo jesu
Gbogbo ohun aye yi
Asan ninu asan
Omule mofo laye
Gbe oju re soke
Ko wa wo jesu to fe o
Yo gba ola laye
Yo mu o wole ogo
Ore wa wo jesu
Gbogbo ohun aye yi
Asan ninu asan
Omule mofo laye
Gbe oju re soke
Ko wa wo jesu to fe o
Yo gba ola laye
Yo mu o wole ogo