Kokoro Wura Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2001
Lyrics
Kokoro to shi lekun ile oluwa
To shi lekun owo agbara re
To shi lekun tubu fawon ounde
Ore ewa, jekalo
Senu ona ile oluwa
Ka le e korin, ka le gbagbara re
Kokoro to shi lekun ile oluwa
To shi lekun owo agbara re
To shi lekun tubu fawon ounde
Ore ewa, jekalo
Senu ona ile oluwa
Ka le e korin, ka le gbagbara re
Orin iyin ni kokoro ile oluwa
Ope ni n mi owo agbara re
Eje kalo oh sagbala jesu mi
Ka le e korin ka si gbagbara re
Kokoro to shi lekun ile oluwa
To shi lekun owo agbara re
To shi lekun tubu fawon ounde
Ore ewa, jekalo
Senu ona ile oluwa
Ka le e korin, ka le gbagbara re
Adura igba gbogbo la i si ope
Ko le e shi lekun oluwa
Eho eyo kinu olorun dun oh
Yo se iyanu laye re
Kokoro to shi lekun ile oluwa
To shi lekun owo agbara re
To shi lekun tubu fawon ounde
Ore ewa, jekalo
Senu ona ile oluwa
Ka le e korin, ka le gbagbara re
Jehosafati, loju ogun
Oyan akorin ogo si oluwa
Ko lo ofa, ko lo ibon
Ogun orun lo ja ogun na to se
Ninu orin ogo
E ma a yin, ke le roju rere re o
Yo se ìyanu laye e re
Kokoro to shi lekun ile oluwa
To shi lekun owo agbara re
To shi lekun tubu fawon ounde
Ore ewa, jekalo
Senu ona ile oluwa
Ka le e korin, ka le gbagbara re
Paul ati sila ninu tubu
Won korin ope, won korin iyin
Lekun tubu shi funwon, ide e won ja
E ho e yo kide aye yin ja
Iyanu yo se laye e re
Kokoro to shi lekun ile oluwa
To shi lekun owo agbara re
To shi lekun tubu fawon ounde
Ore ewa, jekalo
Senu ona ile oluwa
Ka le e korin, ka le gbagbara re
Oun o gbadura si, ti ko se e se
Yi si ope
Adura n mi owo olorun nikan
Ope lo n mi gbogbo ite olorun
Oya ka ma yin, kale roju rere re oh
Yo gba ogo laye e re
Kokoro to shi lekun ile oluwa
To shi lekun owo agbara re
To shi lekun tubu fawon ounde
Ore ewa, jekalo
Senu ona ile oluwa
Ka le e korin, ka le gbagbara re
Hallelujah nikan, lorin orun
Oun si lede orun
Dupe laye ko le mo borun tiri
A o ma rin oh ninu ogo oluwa
Oun funrare ngbe inu iyin wa
Ewa ka lo oh sagbala jesu mi
Ka le e korin, ka le gbagbara re
Kokoro to shi lekun ile oluwa
To shi lekun owo agbara re
To shi lekun tubu fawon ounde
Ore ewa, jekalo
Senu ona ile oluwa
Ka le e korin, ka le gbagbara re
Oya Oya
Ore ewa
Jekalo, senu ona ile oluwa
Ka le e korin, ka le gbagbara re
Ore ewa
Jekalo, senu ona ile oluwa
Ka le e korin, ka le gbagbara re
Ore ewa
Jekalo, senu ona ile oluwa
Ka le e korin, ka le gbagbara re
Ore ewa
Jekalo, senu ona ile oluwa
Ka le e korin, ka le gbagbara re (o ti ya)
Ore ewa
Jekalo, senu ona ile oluwa
Ka le e korin, ka le gbagbara re
Oti ya oh
Ore ewa
Jekalo, senu ona ile oluwa
Ka le e korin, ka le gbagbara re
Oya Oya
Ore ewa
Jekalo, senu ona ile oluwa
Ka le e korin, ka le gbagbara re
Oo ti ya
Ore ewa
Jekalo, senu ona ile oluwa
Ka le e korin, ka le gbagbara re
E je ka ma yin
Ore ewa
Jekalo, senu ona ile oluwa
Ka le e korin, ka le gbagbara re
Ogun aye wa se
Ore ewa
Jekalo, (alagbara) senu ona ile oluwa
Ka le e korin, ka le gbagbara re
E je ka lo oh
Ore ewa (oti ya)
Jekalo, senu ona ile oluwa
Ka le e korin, ka le gbagbara re
Oti ya oh
Ore ewa
Jekalo, senu ona ile oluwa
Ka le e korin, ka le gbagbara re
Oya Oya
Ore ewa
Jekalo, senu ona ile oluwa
Ka le e korin, ka le gbagbara re