
Know Person Lyrics
- Genre:Afrobeat
- Year of Release:2021
This song is not currently available in your region.
Try the alternative versions below.
Alternative versions:
Lyrics
Know Person - Sean Tizzle
...
Finito!!!
Ṣe o d'ayé mo
àní ṣe o d'ayé mo
Tizzle, uh uh
Ṣe o d'ayé mo
àní ṣe o d'ayé mo
awọn t'emi n bẹ ladega
ọmo oko no bẹ prodigal
Ṣe o d'ayé mo
ọmo dakun d'ayé mo
máa lo gbé bo o
kò sẹni tó lè d'ayé mo
ori mi máa jẹ n r'ija ayé
eleda mi jọọ máa gba aboode
make dem no take me do yeye
kan máa béèrè pé ọlọrun mi dà
ori mi máa jẹ n r'ija ayé
eleda mi jọọ máa gba aboode
make dem no take me dó yeye
kan máa béèrè pé ọlọrun mi dà
I keep on moving, ko sí àsìkò o
wọn yaa bo, máa lo duro
ọmo èèyàn tí soro
oya keep on moving, keep it on a low
omo to baa ti gb'owó o
wọn fẹ jẹ é to the the bone uh uh
let your body
mo dé fe mo nkan to bade
to ba je owó ní, esha lo baade
uh uh, esha lo baa dé, that your body
Ṣe o d'ayé mo
àní ṣe o d'ayé mo
awọn t'emi n bẹ ladega
ọmo oko no bẹ prodigal
Ṣe o d'ayé mo
ọmo dakun d'ayé mo
máa lo gbé bo o
kò sẹni tó lè d'ayé mo
ori mi máa jẹ n r'ija ayé
eleda mi jọọ máa gba aboode
make dem no take me dó yeye
kan máa béèrè pé ọlọrun mi dà
ori mi máa jẹ n r'ija ayé
eleda mi jọọ máa gba aboode
make dem no take me dó yeye
kan máa béèrè pé ọlọrun mi dà
dance on all, to the rythm
tell the DJ to put it on repeat
Oya turn it up o, turn it down
make the gbedu enter your body
make you start to totori eyy
forget the story eyy
ọmo je n debe
let your body
mo dé fe mo nkan to bade
to ba je owó ní, esha lo baade
uh uh, esha lo baa dé, that your body
Ṣe o d'ayé mo
àní ṣe o d'ayé mo
Tizzle, uh uh
Ṣe o d'ayé mo
àní ṣe o d'ayé mo
awọn t'emi n bẹ ladega
ọmo oko no bẹ prodigal
Ṣe o d'ayé mo
ọmo dakun d'ayé mo
máa lo gbé bo o
kò sẹni tó lè d'ayé mo
ori mi máa jẹ n r'ija ayé
eleda mi jọọ máa gba aboode
make dem no take me do yeye
kan máa béèrè pé ọlọrun mi dà
ori mi máa jẹ n r'ija ayé
eleda mi jọọ máa gba aboode
make dem no take me dó yeye
kan máa béèrè pé ọlọrun mi dà