
Gbeje fori Lyrics
- Genre:Afropop
- Year of Release:2005
This song is not currently available in your region.
Lyrics
Gbeje fori - Sola Allyson
...
Ori mi Tete la Kori oloola ma pe e ran nise
Eda mi Tete la ke'da oloola maa pe e ran nise
nje alaro jinle nipa oloola to ran wa wasaye
Eja ka si kele nitori ola, egbe je fori
Egbe je fori /2ce Ohohohoh
egbeje fori
Ori lo mo oloola bo d'ola
Eja ka sikele nitori ola, egbe je fori
Ori a f'elomiran pamo, K'aye maa ba fi pamo
Majesi atile j'iya die, ko ma ba j'iya ayeraye
Ologbon aye e maa gbo, Oloye aye O e f'oye gbe
ko seni to mo ibi t'ohun re, Eleda lo mo ola eni
Ema sare ola kol'oshi, Omo Eniyan Egbeje
mu Ise Owo re pelu itelorun eni to ma lo'la maa lo'la
(Egbeje) Egbeje fori (E-gbeje) Egbeje fori Oooo egbeje fori, Ori lo mo oloola bo d'ola eja ka sikele nitori ola egbe je fori
Akunleyan la'daye ba, a de'le aye tan oju nro ni.
sekele koma Siwa Wu nitori Oro joor maa gbo
Teti re beleje gbo mhi ye, Ise adeeda koseni to ye
B'oni ti ri ola o leri bee, eyi mo mo oda mi loju
Ma f'oni b'ola je ko Le San o ninu aye
igba olu oran ko to Koko obe, Omo Eniyan fe'so w'ola
(Instrument)
Ori mi Tete la Kori oloola ma pe e ran nise
Eda mi Tete la ke'da oloola maa pe e ran nise
nje alaro jinle nipa oloola to ran wa wasaye
Eja ka si kele nitori ola, egbe je fori
(Egbeje) Egbeje fori (E-gbeje) Egbeje fori Oooo egbeje fori, Ori lo mo oloola bo d'ola eja ka sikele nitori ola egbe je fori
Ewo eni Tori oshe lolooro koba ra alaafia Fi shaye
onje ohunmu ohunwo'so ohun ri'le gbe ko ni itelorun rara
ose wahala titi titi of'ori w'ori o sare w'ola
Boti d'olooro tan ofo San le iku wo'le omu lo. Ki lo'la ti e wa s'aye da, nitori Oro aye d'ojuru
Iba sepe amo ta laro jinle, Eda iba ma gbe je fori
(Egbeje) Egbeje fori (E-gbeje) Egbeje fori Oooo egbeje fori, Ori lo mo oloola bo d'ola eja ka sikele nitori ola egbe je fori
(Instruments)
Igi gbigbe duro tutu nwo lule, Eledua maa loye
Omi wo yanrin kerere, talo leso boseje
Salamotu ni'yewu safu le'nkule, ebu sowo loja oluwa loye
Ipin la bawaye Ori loni se, ore mhi fe'so w'ola
Maa ma binu Sulemonu nitori or'owo fi saye
Aditu loro Eledumare, Ola asan e se jeje
(koya Gbeje) Ko ya gbeje fori (Ko ya-gbeje)Ko gbeje foriii Oo gbeje fori, Ori lo mo oloola bo d'ola ko ya sikele nitori ola egbe je fori
(Egbeje Egbeje) Egbeje fori (E-gbeje) Egbeje fori Oooo egbeje fori, Ori lo mo oloola bo d'ola eja ka sikele nitori ola egbe je fori
Egbeje fori
Egbeje fori
Abuja osi lorun ope o
Egbeje fori
Eyi to Yan Loma ri
Egbeje fori
Ope loye Eleda fun anfanni
Egbeje fori
O to ju gbogbo ogo iyin ola
Egbey fori
Ayo to fifunwa kole je ko wo, ko pe Egbeje
Egbeje fori
Egbeje Fori
Egbeje Fori
Ona to gba lati sise sogbo oo
Egbeje fori
Esekele fo'la
Egbeje fori
Ema sare ola kol'oshi
Egbeje fori
Omo Eniyan egbeje
Egbeje fori
Egbeje o
Egbeje fori