
Mo Juba Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2018
Lyrics
[
Mo juba oba
Mo juba oba
Iba eledumare to ni gbogbo ogo
Aterere kari aiye olorun awon omo ogun
Mo juba oba
Mo juba oba
Iba eledumare to ni gbogbo ogo
Aterere kari aiye olorun awon omo ogun
Mo juba oba
Iba eledumare oba to ni gbogbo aiye
Eni nla to nbe lori ite titi lailailai
Emi mi bola fun o
Lati ogbun okan mi, mo yi ka otun
Mo yi ka osi mo pa rubu rubu
Fe ni na oba aponle julo eni aiyeraye
Iwo lo tin be iwo yio si ma be
Leyin re ko si mo oba titi lai
Mo sin o mo sin o o sin o lati ogbun emi mi
Eni na oba na oluwosan alanu
Gbogbo eda ati emi ahun bu ola fun o
Mo juba oba
Mo juba oba
Iba eledumare to ni gbogbo ogo
Aterere kari aiye olorun awon omo ogun
Mo juba oba
Iwo ni oba ti o le papo da lailai
Oba to ti wa ti yio si ma be titi
Aiye mi yio ma fi ibukun fun oruko re
Ileke ola ipinle oye opin gbogbo ola
Gbogbo ise yio ma yin o aahn pe o loba
Iwo ni alanu to fe bu se mi loso
Otun fi ogo die kun fi gun mi lade
Odo re na ni mo gbogo na pada si oluwa
Eni na oba na oluwo san alanu
Gbogbo ise da ati emi ahn bola fun o
Gbogbo ise da ati emi ahn bola fun o
Ohun ta ri ati eyi ta o ri won bola fun o
Won bola fun o
Loko orun lagbede meji ile tan te
Ahun bola fun o
Iwo lo ni ike to po alanu to po, olola to po
Ahun bola fun o
Ko sede na ni gbogbo aiye ti iro ogo re kin buyo
Ahun bola fun o
Iru okun bola fun o osa na bola fun o
Ahun bola fun o
Gbogbo ise gbogbo ede ijoba lon wa riri fun oruko re
Ahun bola fun o
Gbogbo ise ati emi
Ahun bola fun o