ÌRÌ Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2019
Lyrics
IRI
Written by Sola Allyson
Produced by Music Magnate
Gbe mi wo l'otun mo te'wo
Ìri k'ó se le mi o
Gbe mi wo l'otun mo te'wo
Ìrì ko se le mi o
Imole k'ó tan l'otun s'ona mi
(Ko tan ko tan ko tan ko ni ku lailai, itura ko ba)
Itura k'ó ba le mi lat'odo Re
(Oluwa t'Ó ni emi mi)
Gbe mi wo l'otun mo te'wo
Ìrì k'o se le mi o
Repeat
Ad lib: Mo jowo emi mi fun O Enit'O ni emi mi
Imole k'ó tan
Imole lat'oke wa k'ó tan
Enit'O fi ebun se mi l'oso
Gbe mi wo, gbe mi wo l'otun
To mi s'ona lati rin Olutona mi
Okunkun k'ó ká kuro tan'mole otun, ki nrin l'ona naa t'oO fe oye k'o ye mi, maa ri maa mo oye á ye mi ninu ife Re
Gbe mi wo, etc.
Ad lib: Mo jowo emi mi fun o, Enit'O ni emi mi
Gbe mi wo l'otun, mo jowo okan mi fun O Enit'O ni okan mi
Mo te'wo mi o lat'oke wa iri ko se, ko se, ko se, ko se le mi
Imole ko tan, ko tan ko tan ko ni ku lailai, imole ona mi o ni ku lailai, itura ko ba o, o ba, o ba, o ba le mi lat'odo Re.
Irin aye o see da rin lai si emi Re, mo jowo okan mi fun O Enit'O ni okan mi
Nigbati idanwo ba de
- Oluwa so mi
Ona maa nsu nigba mi, nigbati ona mi ba su Oluwa o - Adaba to mi
Imole lat'orun k'ó tan s'ona mi, ko maa tan nigbagbogbo o
- Ona yen k'o mase di
Agbara l'aye at'orun owo Re lo wa kos'elomiin l'eyin are - Iwo nikan ni
Iwo nikan naa n mo fe
- Saa maa to mi lo
Nigbati o re okan mi o
- Ìrì se le mi o
--- www.LRCgenerator.com ---