Ohun Ani Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2002
Lyrics
Oba oo oba alase oba
Oba o oba alase oba o
Ki len un fi oba pe
Oba oo oba alase oba x4
(Poetic recitation)
Mo ni o tooooooo
Baba o too ninu olu simi aito akabakun
Naani naani naani
Omo olola naani ola
Ase kita naani epo igi
Omo were ni grandfather oun le bu igi je
Egberin ooo
Oun ani x4
Oun ani lan gbe laruge x4
So precious is the lord to us
So faithful
He will never change through all the age
That is why we jubilate and celebrate
Ohun ani x8
Cant compare to your majesty ehhh
I am lifted up above all the earth
When I think of what the lord has done for me
I cant help but just saying ohun ani
Ohun ani x4
La n gbe x4
Laruge
Ohhhhhhhh yeahhhh oh oh oh yeah
Ohhhhh yeahh ohhhh yeah
Oun ani lan gbe laruge x4