Yin Baba Logo Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2008
Lyrics
E ba mi yin baba logo
E ba mi gbe jesu yi ga
Ope ni fun o
Olurun ife
E ba mi yin baba logo
E ba mi yin baba logo
E ba mi gbe jesu yi ga
Ope ni fun o
Olurun ife
E ba mi yin baba logo
Kilonse, O gbani la
Kilonse, O wo ni so
Kilonse, O gbani la
Kilonse, O wo ni so
O gbani la
O wo mi so
Mimo mimo mimo
Olodumare
Ni kutu kutu ni iwo yi o gba oluwa
Mimo mimo mimo
Fun oun ti o ju lo
Ologo meeta layo ibukun
Layo ni ibukun
Layo inukun
O gbani la
O wo ni so
O gbani la
O wo ni so
Oun, oun oun oun
O gbanila, o gbanila
Oun oun
Mo ni o toooooooooo
Baba ni o to ni ilu ai simi
Aiku ni ilu ooni aikun abukun
Naani naani naani
Omo olola naani ola
Ase kita naani epo igi
Omo were ni grandfather oun le bu igi je
Eyin la riro ala
Alewe ti je alese
Alapa kaabi kaabi
Adeda, ameda eleda, aseda
A tite pon da emi ni beeru
A to pi e ogbon
Ato pe yi oun gbogbo
Ebiti oke, ebiti oke, ebiti oke
Tin fi papa de satani mole
Oba nla..oba nla
Oba nla… oba nla
E ba mi yin baba logo
E ba mi gbe jesu yi ga
Ope ni fun o
Olurun ife
E ba mi yin baba logo
O gbani la
O wo ni so
O gbani la oyigiyigi
O wo ni so oluwosun mi
O gbani la
O wo ni so
O gbani la
O wo ni so
O gbani la
O wo ni so
O gbani la
O wo ni so
O gbani la
O wo ni so