
Surulere Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2008
Lyrics
Su- ru- le –re oh
Ahahahahahaah
E sun mo bi, oya,
E farabale ka sere
E farabale ka sere oloyin
E farabale ka sere
E farabale ka sere oloyin oh
E je ka mu ijoko o
Ka mu ijoko sa sa agba
Eeto to ma mu ogbon wa
O ye ka lowo
Ka lowo ka lola, ka ra motor repete
Ka ni ile lori sugbon ka tun ni suru
Surulere ohhhh
Surulere oh
Oh oh eh eh eh
Eh
O ni baba kan, baba olowo olola
Baba motors
Baba petroleum
Mbc oh
Ile ise repete
Popular jingo
Philanthropist ni baba
O se fun onile o tun se fun alajo
Oba orun eyi ni mo fe
Kin lowo ki mo owo, kin tun mo olorun
Oh yes ki oro mi le dayo oh
Koro mi le dayo, koro mi le dayo
Ah oye koro mi le dayo
Koro mi le dayo, koro mi le dayo
Ah oye koro mi le dayo
Owo fe oju mo won,
Owo fe ju mowon o ehhh
Owo fe ju momo o baba
Owo fe ju momo ehhhhh
Owo fe ju momo o
Owo fe ju momo ah
Iku je ogede, iku re di mole
Iku ko mo pe oun to dun, ko mo pe oun to dun
Ko mo pe oun to dun ba nil aye oh
Kini omo o fowo se ehhhh
Kini omo fowo se ah eh ah ehhhhh
Pasaga paraga
E funmi ni tibi
Oni je ku je
Iku ko mo pe oun to dun, ko mo pe oun to dun
Ko mo pe oun to dun ba nil aye ohhhhhh
Ba o ba mo bi a mi re
Sebi a mo ibi a ti waaaaaaaaa
Ba o ba mo bi a mi re
Sebi a mo ibi a ti waaaaaaaa
Omo eni e buuru ka fi fun ekun pa oh
Omo eni e buuru ka fi fun ekun pa oh
Baba gba mi o mo ma yege
Mo ma yege oh iye mo moye ge
Iye iye mo ye ge, iye mo yege oh
Baba gba mi iba mi ma seun oh
Ibi mi ma seun oh, iba mi ma seun
Iba iba, iba mi ma seun oh, e ba mi ma seun o
Iba iba, iba mi ma seun o, iba mi ma seun oh
Ayo o ni yo re oh, ayo x4
Mayo mayo mayo mayo x4
Ayo o ni yo re oh, ayo x4
Mayo mayo mayo mayo x4