Ki Lan F'oba Pe Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2002
Lyrics
(Poetic recitation)
Oba oo oba alase oba x4
Ki le un fi oba pe
Oba oo oba alase oba
Ki len un fi oba pe
Oba oo oba alase oba
Oba toto bi aro
Oba oo oba alase oba
Oba to wewu oye
Oba oo oba alase oba
Kabiosi oluwa meta lookan
Iwo lalagbada ina, alawo tele orun
Jesu olugbala, arugbo ojo
Eleburu ike, ajanaku koja, mo ri nkan firi
Ah Jesu yi ju oba lo ah
Moni Ki le un fi oba pe
Oba oo oba alase oba
Ki len un fi oba pe
Oba oo oba alase oba
Oba toto bi aro
Oba oo oba alase oba
Oba to wewu oye
Oba oo oba alase oba
E ranti pharaoh o bolorun figabgaga
O sebi kosi oba
Komo pe oba ju oba lo
Nebuchadnezzar nko o yaju si oba mi loke
Sebi logo ni baba loke, so di erepo igbe
Aiye ki le un fi oba pe
Oba o oba alase oba
Moni ki le un fi oba pe
Oba oo oba alase oba
Oba toto bi aro
Oba oo oba alase oba
Kabiosi to wewu oye
Oba oo oba alase oba