![A Dara!](https://source.boomplaymusic.com/group2/M00/08/F8/rBEeM1gh99uAVElqAADc5LGrwi0934.jpg)
A Dara! Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2016
Lyrics
Ahahahahaah a dara
A dara, a dara, a dara, a dara
Okan mi bale tori mo ni oluwa
Moni ireti ayo oh moni baba
Mowa fun okan mi ni isimi
Tori mo ni oluwa
Ara a tun mi tori momo wipe mo mi baba
Baba awon oba ni baba mi
Atobajaiye mi ayole mi
Aseda orun mi baba ti moni
Akoda aiye ni ogo aiye mi
Eyin lon ni mi bi
Eyin logun mi, eyin ni ireeti mi
Apaata aiye raiye
Eyin lon ni mi bi
Eyin logun mi, eyin ni ireeti mi
Apaata aiye raiye
Kosi ipa to le boo go aiye mi
Tori moni oluwa ahhaha
Iji aiye ka kole gbe me mi moni baba rara
Ta lo le pa eni ti olorun o pa tori moni oluwa
Mo fun okan mi ni isimi, moni baba
Nitori pe Baba awon oba ni baba mi
Atobajaiye mi ayole mi
Aseda orun mi baba ti moni
Akoda aiye ni ogo aiye mi
You are my everything
Eyin logun mi, eyin ni ireeti mi
Apaata aiye raiye
Eyin lon ni mi bi
Eyin logun mi, eyin ni ireeti mi
Apaata aiye raiye
Ojo ola a dara, ojo ola adara
Emi ti gbe okan mi le oluwa
Ojo ola a dara
Mo gbe okan mi le oluwa
Ojo ola a dara ah
Ojo ola a dara, o jo ola a dara
E je ki a gbe okan wa le oluwa
Ojo ola a dara
Mo gbe okan mi le oluwa
Ojo ola a dara
Ni ile ni oko, a dara
Lono ojo, a dara
My tomorrow, a dara
In my life in the whole life, a dara
Yes he will, a dara
A dara, a dara
Cheer up my brother, a dara
Don’t give up on yourself, a dara
For I know for sure a dara
Tomorrow go better, e go better, e go better