Onisegun Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2016
Lyrics
Onisegun lawa ni
Jesu a bani da re
Oro re mu ni laara da
A gbo oun ti jesu
Iro didun lori sarah
Oruko didun ni ooo
Orin to dun ju lo ni
Jesu jesu jesu
Gbani gbani aiye
Oloruko repete, ekun oko pharaoh
Awagbaro ma gbe je
Oba tin fi oba je
Oba tin fi oba loye
Father we worship you
Iro didun lori sarah
Oruko didun ni ooo
Orin to dun ju lo ni
Awa pe jeeeeeeeeeeeeeeeeeesu
Jesu,
Oh I love to sing your name
Halleluyah