Eyo Ninu Oluwa/Afope F'Olorun Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2016
Lyrics
Eyo ni oluwa eyo
Eyin tokan re se le gbe
Eyin to si gbo oluwa eh
Le banu je a ta lero
Eyo eyo, eyo eyo
Eyo ninu oluwa eyo
Eyo eyo, eyo eyo
Eyo ninu oluwa eyo
Come on put your hands together
Ohhhh come on one more time
Rejoice in the lord oh rejoice
Oh rejoice, rejoice
Rejoice rejoice, rejoice
Rejoice in the lord rejoice
Rejoice rejoice, rejoice
Rejoice in the lord everyone
Afope fun olorun
Lokan ati lohun wa
Eni se ouniyanu,
Ni eni ti araye yan
Nigba ti awa ni omo owo
Oun naa lon toju wa
Osi fun ebun ife
Se itoju wa sile
Oba oni bu ore
Ma fi wa sile lai lai
Ayo ti koni opin
Oun ibukun yio je tiwa
Awa omo inu ore
Towa dagba mu
Yo wa ninu ibi
Laiye ati lorun
Afin yin o pe
Si olorun baba orun
Ati mimo,
Ti o ga ju lo o
Olorun kan lai lai
Taiye ati orun
Leni o wa disin
Eni yi o wa lai lai