Oreke Lewa Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2014
Lyrics
Oreke lewa omoge abeje siso
Oreke lewa omoge abeje siso
Abi fe loju atokan to mo lolo
Oni nu re olokan re ti ko leni kan ninu afi ko se jeje
Oni wa re o oni nu ire
Bo ti yan tire o yato si temi
Bi mo ti yan temi o ya to si tire
Dakun ma se wemi mo ore mi
Dakun ma se wemi mo ore mi
Isele to sele si eyan o ba waiye
Lala wa wahala wa bi ko ba wun eleda ko a ko ba se lasan
Ma jowu enikeji ko lo se si olorun
Tori bo ti yan tire o yato si temi
Bi mo ti yan temi o yato si tire
Oreke lewa omoge abeje siso
Oreke lewa omoge abeje siso
Abi fe loju atokan to mo lolo
Oni nu re olokan re ti ko leni kan ninu afi ko se jeje
Oni wa re o oni nu ire
Bo ti yan tire o yato si temi
Bi mo ti yan temi o ya to si tire
Ona ti olorun gba sise ologbon aye kan o le so
Ona Ona ti olorun gba sise ologbon aye kan o le so
Eni aye dara fun o ko gbe jeje
Eni to o ri se e ma ro aropin
Ba ba si wa laiye igba tiwa a de
Alara lo fi wa sara afi ka bebe si
Bo ti yan tire o yato si temi
Bi mo ti yan temi o yato si tire
Oreke lewa omoge abeje siso
Oreke lewa omoge abeje siso
Abi fe loju atokan to mo lolo
Oni nu re olokan re ti ko leni kan ninu afi ko se jeje
Oni wa re o oni nu ire
Bo ti yan tire o yato si temi
Bi mo ti yan temi o ya to si tire
Ojo to ro si ewuro lo ro si ireke
Ojo to ro si ewuro lo ro si ireke o
Ile to mi sosan na lo mi si orogbo
Ise olorun ni ko si un ti a le se
Alara lo ni to ba se ara afi ka se je
Bo ti yan tie o yato si temi
Bi mo ti yan temi o yato si tire
Oreke lewa omoge abeje siso
Oreke lewa omoge abeje siso
Abi fe loju atokan to mo lolo
Oni nu re olokan re ti ko leni kan ninu afi ko se jeje
Oni wa re o oni nu ire
Bo ti yan tire o yato si temi
Bi mo ti yan temi o ya to si tire
Dakun ma se wemi mo ore mi
Dakun ma se wemi mo ore mi
Isele to sele si eyan o ba waiye
Lala wa wahala wa bi ko ba wun eleda ko a ko ba se lasan
Ma jowu enikeji ko lo se si olorun
Tori bo ti yan tire o yato si temi
Bi mo ti yan temi o yato si tire
Oreke lewa omoge abeje siso
Oreke lewa omoge abeje siso
Abi fe loju atokan to mo lolo
Oni nu re olokan re ti ko leni kan ninu afi ko se jeje
Oni wa re o oni nu ire
Bo ti yan tire o yato si temi
Bi mo ti yan temi o ya to si tire
Bo ti yan tire o yato si temi
Bi mo ti yan temi o ya to si tire
Bo ti yan tire o yato si temi
Bi mo ti yan temi o ya to si tire
Bo ti yan tire o yato si temi
Bi mo ti yan temi o ya to si tire