Aye O fe Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2014
Lyrics
Ao rin nile inu bi elesin
Ao wo akisa inu bi alaso
Ao je bosan inu bi eleran
Opo alangba dakun dele inje ati le mo bi inu run won
Aye o fe o eniyan fe
Aye o fe o eniyan fe
Eniyan o fe ka gberu dori
Ori eni ni ba ni gbe
Aye o fe ka ru eru ka so ori eni ni nan i yo ni
Lamori doloro laiye fe un
Okapa soke o fanda
Ko woju ile bo ti le yon i
Ko laro jile pe enkule lota wa
Inu iyewu laseni gbe
Aye o fe o eniyan fe
Aye o fe o eniyan fe
Eniyan o fe ka gberu dori
Ori eni ni ba ni gbe
Aye o fe ka ru eru ka so ori eni ni nan i yo ni
Ore da sikira o sukun kiri abi ko mo pe eni abinibi dani
Ah kote gbon alayi gbo aye
O fi nu won ore inu re undun
Ko mo pe erin ita ko ni ife denu
Aye o fe o eniyan fe
Aye o fe o eniyan fe
Eniyan o fe ka gberu dori
Ori eni ni ba ni gbe
Aye o fe ka ru eru ka so ori eni ni nan i yo ni
Eni a ni ko feni loju to fata senu
Eni a ni ko kini leyin o fegun sowo
Eni aba foro lo alaro kiri ni
O ba te segi ko se I eni gun
Ko wo eni to ma se idaro e
Aye o fe o eniyan fe
Aye o fe o eniyan fe
Eniyan o fe ka gberu dori
Ori eni ni ba ni gbe
Aye o fe ka ru eru ka so ori eni ni nan i yo ni
Ao rin nile inu bi elesin
Ao wo akisa inu bi alaso
Ao je bosan inu bi eleran
Opo alangba dakun dele inje ati le mo bi inu run won
Aye o fe o eniyan fe
Aye o fe o eniyan fe
Eniyan o fe ka gberu dori
Ori eni ni ba ni gbe
Aye o fe ka ru eru ka so ori eni ni nan i yo ni
Shey bi ore lo da o o roju koko
Oti gbagbe pe eni abi n bi dani
Shey bi eyin kule re n iota wa
Inu ile re gangan ni asebi gbe
Fesan rin nile oma un yon i
Aye o fe o eniyan fe
Aye o fe o eniyan fe
Eniyan o fe ka gberu dori
Ori eni ni ba ni gbe
Aye o fe ka ru eru ka so ori eni ni nan i yo ni
Iwo eniyan to jaiye layi bikita
Abi o ti gbagbe ofin oluwa
To sofun wa ka rora ma se
Eso lolaiye ka simi edo
Ka wojuile rin tori ile loju