
Malaika ft. Bien Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2024
This song is not currently available in your region.
Lyrics
Malaika ft. Bien - Teni
...
intro
sitolia sitaogopa
bwana wa majeshi ametenda
(eli elijah)×2
mbinguni leo malaika wanaimba
eli elijah
eli elijah
mbinguni leo malaika wanaimba
malaika wanaimba ooh x3
Yi o ti ma loo
Mo l'Olùwà
Bo ti le-le ju, orúkọ rẹ
pre-chorus
Eli, Elijah
Eli, Elijah, ah-ah
Ọrun ṣi ilẹkun
Malaika sọkalẹ wa
Eli, Elijah o
chorus
Eli, Elijah (eh-eh, eh)
Eli, Elijah, ah-ah (eh-eh, eh)
Ọrun ṣi bo'lẹ
Malaika sọkalẹ wa
Malaika sọkalẹ wa o (Malaika sọkalẹ wa)
Malaika sọkalẹ wa o (Malaika sọkalẹ wa)
verse
I'm at peace with God, and at peace with myself (uh-whoa, uh-whoa)
I surrender, I surrender
No weapon fashioned against me shall prosper
Back to sender (mo ni back to sender o), back to sender (mó ni back to sender o)
verse
Lord, I give You my heart, and my soul, and devotion
You give me peace of mind
And I see all Your works and the good that You are doing
Ṣebi na You change my life
bridge
Ògo ní, ògo ní, ògo ní fún Baba
Ògo ní fún Ọmọ
Ògo ní, ògo ní, ògo ní fún Ọlọrun Ẹmí Mimọ
Ògo ní, ògo ní, ògo ní fún Bàbá
Ògo ní fún Ọmọ
Ògo ní, ògo ní, ògo ní fún Ọlọrun Ẹmí Mimọ
verse
Thank You for the things that You got me through
Na only me and You
I dey cry night, You dey wipe my eyes
Na You dey give me grace o
You say make I get faith o
Make my faith no deflate o
verse
Don't jump from my plate o
People change, but You remain the same o
Àìmọye èyàn to ń kú lójoojúmọ́
Mi ò fí yọ wọn, mo fí ń dúpẹ ní
Ẹru ń dupẹ ni, mo fí ń dúpẹ ní o
pre-chorus
Eli, Elijah (eh-eh, eh)
Eli, Elijah, ah-ah (eh-eh, eh)
Ọrun ṣi ilẹkun
Malaika sọkalẹ wa
Eli, Elijah o
chorus
Eli, Elijah (eh-eh, eh)
Eli, Elijah, ah-ah
Ọrun ṣi bo'lẹ
Malaika sọkalẹ wa
Malaika sọkalẹ wa o (Malaika sọkalẹ wa)
Malaika sọkalẹ wa o (Malaika sọkalẹ wa)