Boluwatife Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2016
Lyrics
Boluwatife - Teni
...
Ohhhhhhhhh, ohhh yeah
Alright
Ohhuhhhhh
Elelelelele
Ohhhhhh
Ohhhhhh, yeah
Ready
B'Oluwatife, lo n s'ola re ooo
Ehhhhh.....
Ahhhh
K'aye ma pa mi, k'on ma so mi d'idakuda o ooo
Yeah
Eh, omo kekere ano da ooo
Teniola ti d'agbalagba Ahhh
E ma fi mi s'oloso ooo
Ibo l'oju Olohun wa o ooo
Mi o ni pada lo s'eyin
Okay
Adekeye
Adekeye
Se b'awon lo teni fun mi
Won fe ki n jabo
Jabo sinu koto
Won fe ki n ku, kuku ojiji ehhhh
Won fe ki n jabo
Jabo sinu koto
Won fe ki n kuku ojiji ah
B'Oluwatife, lo n s'ola re o ooo
Eh eh
oooo
K'aye ma pa mi, e ma fi mi s'eleya ooo
Eru l'oni
Oba l'ola
Olowo l'aye mo
K'a se daadaa ahhhh
Oooyeah oooo,
Freestyling
Freestyling
And I just want to live my life the way I like
I don't want to cope Ahhh to