Arawọn Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2024
Lyrics
Hnnnn Cabasa bá mi jáwọn, Doctorflowz lóríi beat io
Yurh
Sometimes when I'm lone I go deep in thought
Kíni mò ń ronú kódé bí ò ń ṣe results
Sundays to Thursday pẹ̀lú ọjọ́ Jimoh
Carrying my cross all day mi ò báwọn díbọ́n
Stepping into this game called hustle isn't funny
Sometimes you go vulgar and think bitches only
Bópẹ́ bóyá o, one day one day
Ọ̀rọ̀ bíi ṣìná láyé mi Olúwa á gbé wọn dè
Ṣ'àdúrà kin ṣ'àmín kò sí ìjà ni churchi
Èwo ni ìfojújọ́ ọmọ Ọlọ́run finújẹ́ onírọ́ òsì
Wọn ò le sọ mí ṣókùnkùn torí mo ní torchi
Nán le lérí pán l'óògùn, ẹgbẹ́ wọn ńní Porsche
Nwa! Sọfún Uche kóbi Mba
Pé èwo ni tìgara chicken níbi turkey wà?
Pé èwo ló kan jet i pẹ̀lu títì ò da'a?
Mehn I pray to fly high so k'Ọlọ́hun gbà
Arawọn ò yá ooo
Àwọn jengbetiele
Arawọn ò le
Arawọn ò yá ooo
Eh eehhhh eh
Arawọn ò lé
Àwọn tí ò le fọṣọ wọn kómọ́ fẹ́ma brainwash wa
Lóri p'ọ́nfẹ́ control wọ́nní káwọn pause wa
Bojẹ́ tìjà nán báwá àwa gan ti bá force wá
Àìfẹ́ ka gain wọn tánfẹ́ ṣírò loss wa
If that shits don't stop mehnn I'll stop it
Èwo ni kánma lérí léka whenn I was talking
Orí tán lé tán ò le bá
Ìka tán ní tán ò le kà
Wọ́n le péjọ kán pégba but kán dẹ̀hìn lẹ́yìn flopping
Arawọn ò yá ooo
Àwọn jengbetiele
Arawọn ò le
Arawọn ò yá ooo
Eh eehhhh eh
Arawọn ò lé
Sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ mi ló ń pèdè kí bad belly mérége
Eh eh, kí bad belly mérége
Sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ mi ló ń pèdè kí bad belly mérégé
Kí bad belly mérége