![Orekelewa](https://source.boomplaymusic.com/group2/M00/01/27/rBEeM1fx5EOAN28AAACcdv6OCGY976.jpg)
Orekelewa Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:1998
Lyrics
Orekelewa - Sola Allyson Obaniyi
...
orekelewa omoge, abeje tutu
orekelewa omoge, abeje tutu
abi'fe l'oju At'okan to mo lolo
Oninu 're olokan ire
Ti Ko lenikan ninu Afi ko se jeje
Oniwa're Oninu 're
Bo o ti yan tire, o yato si Temi
Bimo ti yan Temi, o yato si tire
..instrumentals ...
Dakun mase *why me" mo ore mi
Dakun mase*why me" mo ore mi
isele t'yo sele s'eeyan, o ti baa waye
Laala wa ,wahala wa.
Biko ba wu Eleda Nko A o ha ya lasan
ma jowu enikeji, Ko Lo se s'oluwa
Tori Bo o ti yan tire, o yato si Temi
Bimo ti yan Temi, o yato si tire
orekelewa omoge, abeje tutu
orekelewa omoge, abeje tutu
abi'fe l'oju At'okan to mo lolo
Oninu 're olokan ire
Ti Ko lenikan ninu Afi ko se jeje
Oniwa're Oninu 're
Bo o ti yan tire, o yato si Temi
Bimo ti yan Temi, o yato si tire
Ona t'Olorun n gba sise, ologbon aye kan o le so
Ona t'Olorun n gba sise, ologbon aye kan o le so
Eni aye dara fun o, ko gbe jeje
Eni too ri se ,e ma r'aropin
baa ba si wa Laye, Igba tiwa aa de
alara lo fi wa s'ara Afi ka beebe si
Bo o ti yan tire, o yato si Temi
Bimo ti yan Temi, o yato si tire
orekelewa omoge, abeje tutu
orekelewa omoge, abeje tutu
abi'fe l'oju At'okan to mo lolo
Oninu 're olokan ire
Ti Ko lenikan ninu Afi ko se jeje
Oniwa're Oninu 're
Bo o ti yan tire, o yato si Temi
Bimo ti yan Temi, o yato si tire
...instrimemtals...
ojo to ro s'ewuro lo ro si'reke o
ojo to ro s'ewuro lo ro si'reke o
Ile to mi s'osan naa lo mi s'orogbo
ise Olorun ni, ki si un ta le se
alara lo fi wa s'ara Afi ka se jeje
Bo o ti yan tire, o yato si Temi
bimo ti yan Temi, o yato si tire
orekelewa omoge, abeje tutu
orekelewa omoge, abeje tutu
abi'fe l'oju At'okan to mo lolo
Oninu 're olokan ire
Ti Ko lenikan ninu Afi ko se jeje
Oniwa're Oninu 're
Bo o ti yan tire, o yato si Temi
Bimo ti yan Temi, o yato si tire
...instrumentals ...
Dakun mase *why me" mo ore mi
Dakun mase*why me" mo ore mi
isele t'yo sele s'eeyan, o ti baa waye
Laala wa ,wahala wa.
Biko ba wu Eleda Nko A o ha ya lasan
ma jowu enikeji, Ko Lo se s'oluwa
Tori Bo o ti yan tire, o yato si Temi
Bimo ti yan Temi, o yato si tire
orekelewa omoge, abeje tutu
orekelewa omoge, abeje tutu
abi'fe l'oju At'okan to mo lolo
Oninu 're olokan ire
Ti Ko lenikan ninu Afi ko se jeje
Oniwa're Oninu 're
Bo o ti yan tire, o yato si Temi
Bimo ti yan Temi, o yato si tire
orekelewa omoge, abeje tutu
orekelewa omoge, abeje tutu
abi'fe l'oju At'okan to mo lolo
Oninu 're olokan ire
Ti Ko lenikan ninu Afi ko se jeje
Oniwa're Oninu 're
Bo o ti yan tire, o yato si Temi
Bimo ti yan Temi, o yato si tire
Bo o ti yan tire, o yato si Temi (kadara taye Pelu KEHINDE o dogba)
Bimo ti yan Temi, o yato si tire
Bo o ti yan tire, o yato si Temi (kaluku yan lototo ni)
Bimo ti yan Temi, o yato si tire
Bo o ti yan tire, o yato si Temi (ayanmo ni kadara ka ya gba f'Olorun)
Bimo ti yan Temi, o yato si tire
Bo o ti yan tire, o yato si Temi(ka maa se jeje,ka naa gbadura s'Olorun)
Bimo ti yan Temi, o yato si tire
Bo o ti yan tire, o yato si Temi(bimo ti yan Temi o)
Bimo ti yan Temi, o yato si tire