![Lorile](https://source.boomplaymusic.com/group1/M00/01/29/rBEeMVfx7eeASJJuAACccs8jAAs655.jpg)
Lorile Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2005
Lyrics
Lorile ile yi o kin sori re
Lori ile yi o kin je eniyan
Lori ile yi o kin lowo lowo
Ala le ile yi o bami fase si
Lorile ile yi o kin sori re
Lori ile yi o kin je eniyan
Lori ile yi o kin lowo lowo
Ala le ile yi o bami fase si
Olorun bukun Nigeria ka le rire mu
Wara oti oyin to tin san ko ri su re tun si
Ire ko pada di sile wa alale ile jowo bawa se
Ko’si kase ni Nigeria jowo ma je a ri iyan mo lailai
Adeda gbenumi sase kori ile yi beere si sere
Lorile ile yi o kin sori re
Lori ile yi o kin je eniyan
Lori ile yi o kin lowo lowo
Ala le ile yi o bami fase si
Ala le ile yi olu orun bami fase si
Baba rokun baba rosa ile gangan ni ile je
Mo fe roko mo fe rajo ile la bo simi oko
Kori gbere koni nibi taba wa iye gangan ni koko
Nigeria a so wa si rere ka ni suru eyi lo lo jo
Lorile ile yi o kin sori re
Lori ile yi o kin je eniyan
Lori ile yi o kin lowo lowo
Ala le ile yi o bami fase si
Iro nu oda ikan tete kawo kuro lero
Abamo oda ikan ibi oroi danisi langbe
Temi tere lajo se od owo wa toko tabo
Agba jowo lafi saya gbeji owo kan o gberu do ri
Kasowopo ka tun se eledumare a ko wa lowo
Lorile ile yi o kin sori re
Lori ile yi o kin je eniyan
Lori ile yi o kin lowo lowo
Ala le ile yi o bami fase si
Eleya le ya o ye wa rara ifowo sowopo lo se koko
Oye eledumare to ko wa po isokan ma lo fe
Alumoni wa ko ma ma ya wa eni to fun wa ko wa po ni
Ibi ife wa layo gbe ibi ayo wa ire awa
Olorun bukun ile wa ema je a fayo fo
Lorile ile yi o kin sori re
Lori ile yi o kin je eniyan
Lori ile yi o kin lowo lowo
Ala le ile yi o bami fase si
Eni tomi gaga esin iga arare lomi gbe
Olorun o beere olugbe ga ohun to da wa mo ara to da
Alafia wa ma lo je ka tun gbe aye so’go fun igbagbo musulumi
Olorun kan la ke si kasowopo ka bebe si ko le pada ye gbogbo wa
Lorile ile yi o kin sori re
Lori ile yi o kin je eniyan
Lori ile yi o kin lowo lowo
Ala le ile yi o bami fase si
Iro nu o da ikan tete kawo kuro lero
Abamo o da ikan ibi ori da ni si lagbe
Temi tere la jo se o dowo wa toko tabo
Agba jowo lafi soya agbji owo o gberu dori
Kasowopo ka tun se eledumare a towa lowo
Lorile ile yi o kin sori re
Lori ile yi o kin je eniyan
Lori ile yi o kin lowo lowo
Ala le ile yi o bami fase si
Ala le ile yi o bawa fase si ki ire ko kari
Ala le ile yi o bami fase si
Iwo to mo wa ka to sope a bi o mo ara to fe fi wa da
Ala le ile yi o bami fase si
Bawa fase soro wa ka gbori ile yi seun rere
Ala le ile yi o bami fase si
Base wa ni ka ma ri ba se ri ni ko ma to
Ala le ile yi o bami fase si
Bo se towaa lowo ko je aje monu bo se je aje monu ko ba wa kale
Ala le ile yi o bami fase si
Ba se lu ni ko ma dun ko mama ya mowa lowo
Ala le ile yi o bami fase si
Ka gbori ile yi sohun rere sun wa si waju sun wa si waju
Ala le ile yi o bami fase si
Wara ati oyin to ti san dapada ase re ni
Ala le ile yi o bami fase si
Olowo mekunu ara to wu o lo fi wa da fun wa lounje wa
Ala le ile yi o bami fase si
Ogun abe le bawa fopin si lori ile yin fun wa lala fi a
Ala le ile yi o bami fase si
Eni to ni ile ma gbo bawa fase si ire wa
Ala le ile yi o bami fase si
Oju anu re la bebe fun siju anu re wo wa o
Ala le ile yi o bami fase si
Ala le ile yi o bami fase si
Ala le ile yi o bami fase si