Ibere Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2005
Lyrics
Ibere isere lotun laiye mi onise ara modupe o
Ibere isere lotun lori igba mi eleru niyi ose un o
Ibere isere lotun laiye mi onise ara modupe o
Ibere isere lotun lori igba mi eleru niyi ose un o
Ibere isere lotun laiye mi onise ara modupe o
Ibere isere lotun lori igba mi eleru niyi ose un o
Olorun oshe oba iyanu
Olorun ose modupe o
Olorun ose oba iyanu
Olorun ose modupe o
Opolopo emi loti nu loti lo
O je kin ra rinu baba modupe
Otun funmi lalafia mo ri je mo ri mu olorun ose modupe o
Ore ofe re loso mi di eniyan
Ife aisetan to nisimi loso mi dolori re
Anu re loso mi dalayo
Mimu se ileri re lo mumi wa sope
Oya ma gbo oba mi ma gbo
Ma gbo olu pe mi ma gbo
Titi aiye ni ma yin o fun anu re titi aye ni ma yin o fun ife re
Ibere isere lotun laiye mi onise ara modupe o
Ibere isere lotun lori igba mi eleru niyi ose un o
Ibere isere lotun laiye mi onise ara modupe o
Ibere isere lotun lori igba mi eleru niyi ose un o
Adeda ose oba iyanu olorun ose modupe o
Alorun alaye olorun ose oba iyanu olorun ose modupe o
Opolopo emi loti nu loti lo
O je kin ra rinu baba modupe
Otun funmi lalafia mo ri je mo ri mu olorun ose modupe o
Oju ise lara mi odasan
Opa ibanuje mi re egan mi wa dogo
Kini mo je olorun to fi pe mi sola
Opelope re lara mi ah modupe
Odori mi lare oba ti kin setan
Odori mi lare oba ti kin setan
Oshe oshe oshe alayo mi fun mumuse ileri re
Ibere isere lotun laiye mi onise ara modupe o
Ibere isere lotun lori igba mi eleru niyi ose un o
Emi lo se yi fun tan olorun o seun
Emi lo seyi fun tan o baba mi olorun oseun
Egan mi dogo ola re ni
Olorun to sola funmi to tun fayo bami
Oruko re to yi oba olola
Emi lo se yi fun tan olorun o seun
Emi lo seyi fun tan o baba mi olorun oseun
Egan mi dogo ola re ni
Olorun to sola funmi to tun fayo bami
Oruko re to yi oba olola
Nigbati ibanuje de ko salabaro Kankan
Iwo lo wa funmi o olola
Arokan ya ko kan mi eku asurin oje mi ni
Sugbon o pa ibanuje mi re eleto aye mi oshe o
O segan mi d’ogo ologo re o o foro mi s’ogo
Titi aye o ogo a yin o eni to so’ju okan mi modupe
Emi lo se yi fun tan olorun o seun
Emi lo seyi fun tan o baba mi olorun oseun
Egan mi dogo ola re ni
Olorun to sola funmi to tun fayo bami
Oruko re to yi oba olola
Gbogbo eniyan ewa bami dupe
Kko ma soun t’olorun o le se bo ti le un ki ibanuje le to
A se iyanu mo mo daju
Ore gbekele oluwa ko wuwa toto
Oro re fi’di mule a mu ileri se
Olorun kin se eniyan to sope lailai
Ero re ni ko tun pa ore mi
Alagbara ma lolorun wa toba wun olorun ole soke dile iyen tun ko
Okun di ogbele osupa dile ire ni
Gbekele oluwa o ma to gbo
Emi lo se yi fun tan olorun o seun
Emi lo seyi fun tan o baba mi olorun oseun
Egan mi dogo ola re ni
Olorun to sola funmi to tun fayo bami
Oruko re to yi oba olola
Mo mo’pe wa
Ope riri je ririmu
Mo m’op wa
Ope ipe to pe mi
Mo m’op wa
Olorun mo dupe
Mo m’op wa
Bi ko ba se iwo
Mo m’op wa
Ibo ni ba fo’ju si ibo ni ba wa
Mo m’op wa
Olpe wa gbope mmi
Mo m’op waaaaaaaaaaaaa
Iwo n iwo ma sin iwo n iwo ma bo
Iwo n iwo ma sope si olorun ayo mi
Iwo n iwo ma sin iwo n iwo ma bo
Iwo n iwo ma sope si olorun ayo mi
Iwo to fe wa la o ma sin titi
Olorun olore wa iwo to so wa ninu idanwo
Mimo ogo ola re
Iwo n iwo ma sin iwo n iwo ma bo
Iwo n iwo ma sope si olorun ayo mi
Talaba sin ka ma sope sin
Bi ko se iwo f’ogo olaiyin ati ope to fi fun wa
Odun opo ope ore ofe re ni ah mimo ogo ola re
Iwo n iwo ma sin iwo n iwo ma bo
Iwo n iwo ma sope si olorun ayo mi
Iba ma se pe oti wa fun wa nigba okunkun su
Ota imole to ma jedere fun wa
Ope atokan wa reta mu wa fun o baba mimo ogo ola re
Iwo n iwo ma sin iwo n iwo ma bo
Iwo n iwo ma sope si olorun ayo mi
Iwo n iwo ma sin iwo n iwo ma bo
Iwo n iwo ma sope si olorun ayo mi
Iwo n iwo ma sin iwo n iwo ma bo
Iwo n iwo ma sope si olorun ayo mi