![Iwo Lo Ye](https://source.boomplaymusic.com/group2/M00/01/2F/rBEeNFfyCemACFc4AADHzuhFQfQ826.jpg)
Iwo Lo Ye Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2015
Lyrics
Iwo Lo Ye - Sola Allyson Obaniyi
...
Iwo lo ye
ogo ola
Iwo lo ye
iyi eye
Iwo lo ye
ogo ola
Iwo lo ye
iyi eye
Iwo l'ope to si
Oba mimo
Iwo ni'yin to si
Oba Toto
ikawo re
lohun gbogbo ti wa
Iwo lo ye
ogo ola
Iwo lo ye
iyi eye
Iwo lo ye
ogo ola
Iwo lo ye
iyi eye
Iwo l'ope to si
Oba mimo
Iwo ni'yin to si
Oba Toto
ikawo re
lohun gbogbo ti wa
Iwo lo ye
ogo ola
Iwo lo ye
iyi eye
kabiyesi o
eledumare ooo
to to to Oba
kabiyesi ooo
oba to joko l'ori obiri aye ogo foruko re
to to to oba
to to to Oba
to to to oba
oba ibere
oba aarin
oba to m'eyin to le sohun gbogbo
to to to oba
kabiyesi o awon orun nsoro ogo re ofurufu f'ise re han oo
to to to oba
ise re po gan ni ko lafiwe o, awole afi'yin foruko mimo re
to to to oba
kabiyesi o Baba mi olorun mi eni to l'ebun gbogbo
to to to oba
iba re iba iba to to
to to to Oba
to to olorun Iyanu ogo foruko re
to to to iba
Oba ibere, Oba aarin, Oba to m'eyin to le sohun gbogbo
to to to oba
Oba ibere
Oba ibere, Oba aarin, Oba to m'eyin to le sohun gbogbo
to to to oba
eyin no baba to to baba
eyin no baba to ju baba lo
baba to l'emi mi ogo foruko re
Iwo ni baba to ju baba lo
eyin ni baba to to baba
eyin ni baba to ju baba lo
eyin ni baba to to baba
eyin ni baba to ju baba lo
eyin ni baba to to baba
eyin ni baba to ju baba lo
eyin ni baba to to baba
eyin ni baba to ju baba lo
KO si oo
KO si ooo
KO si ooo
kos leyin re
KO si ooo
KO si ooo
KO si ooo
KO si leyin re
alagbara kan KO ma si
oni'mo kan KO mama si o
KO si ooo
KO si leyin re
Iwo l'oba to l'emi mi,Iwo ni
Iwo sa ni maa fi gbogbo igba mi gbegao o
KO selomiran leyin re,
KO si ooo
ninu aso igunwa to fi Se mi l'oso mo ba ruburubu
mo f'ori bale foruko re ooo
Iwo saa ni ologbon julo
KO si oo
KO si ooo
KO si ooo
KO si ooo
KO si leyin re
KO si oo
KO si oo
KO si oo
KO si leyin re
KO si oo
KO si oo
KO si ooo
KO si leyin re
eyin ni baba
to to baba
eyin ni baba
to ju baba lo
ase ITE fun o ninu okan an wa, Iwo ni,
Iwo ni baba to ju baba lo
inu orin iyin awon eni mimo ni'wo ngbe baba
Iwo ni baba to ju baba lo
oba to joko Lori ITE awon angeli nforibale fun o
Iwo ni baba to ju baba lo
eyin ni baba to to baba
eyin ni baba to ju baba lo
eyin ni baba to to baba
eyin ni baba to ju baba lo
eyin ni baba to to baba
eyjn ni baba to ju baba lo
eyin ni baba To to baba
eyin ni baba to ju baba lo
e ewa e wa wo'ran, baba wa ni
e ewa w'alewilese o,baba wa ni
aalagbawi awao, baba wa ni
o oba to tan'mole sona wa oun ni ,baba wa ni
aye si nbe elese wole wa,baba wa ni
baa wa po ni agbara o po ni Aanu oo, baba wa ni
e he he ha,e lo sinmi agbaja awa ni baba kan to moye
ohun lo tun'le aye awa Se gege
he he he he he ha
e he he ha, e lo sinmi agbaja
awa ni baba kan to m'oye
oun lo tun'le aye awa Se gege
e ewa e wa woran o, baba wa ni
ewa wo olurapada alaanu ton tu'ni sile, baba wa ni
ewa w'alara ire oba ton tu'ni I Se, baba wa ni
eni to wa leyin ogba KO wole wa,baba wa ni
aye si nbe ninu ogba alaanu o, baba wa ni
b'omode sun a fi'sori e so
b'agba ba sun a fi'sori e so
ire la mo toun gbawa low'ewu hallelujah ogo ni fun baba
ki la fi san oo
ki la fi san j'awon t'iku ti pa
Ire lo saabo alafia wa,
ire la ni toun gba wa low'ewu hallelujah ogo ni fun baba
hahahahallelu
hallelujah ogo no fun baba
a ti ri'gbala Ojo oni
alaye ni yoo yin o b'otiye
halleluyah ogo ni fun baba
hahahahahallelu
halleluyah ogo ni fun baba
a f'ijo f'ilu yin olorun wa
alaye ni yoo yin o b'o ti ye
hallelujah ogo ni fun baba
oluwa a a a a
eh eh
oluwa oooo o
eh eh
oluwa oba to mo dafidi fi'sori e so wa
oluwa oba to mo dafidi fi'sori e so wa
oluwa oba to ni'ke Ige fi'sori e so wa
oluwa oba to ni'ke Ige fi'sori e so wa
Ope ye o o eee
Ope
eni to joko l'ori ITE ogo to gba eye,
ope
ope ye o ooo eeeh
ope
ope ye o oo eeeh
ope
ope ye oruko re Iwo nikan ni
ope
KO si ooo
tani nba sin bi o se'wo
oba to f'aanu tan'mole s'ona mi
KO s'elo min l'eyin re
orin yi naa ni emi yoo ma ko
orin irapada imole too tan fun mi
anu mo ri gba okun pada di imole Lona mi
KO si leyin re
ajoda ope laa da
iyin saa la mu wa
ajoda ope ni gbogbo iseda DA
iyin saa la mu wa
f'oba to Lola
olusola to nfunni Lola Se
olupe'ni s'ola
o gbe'nu eni s'ola
talo le s'ola
lai se pe o fun Lola se
ola re lo fun ni Lola
ta fin s'ola ninu re
f'oba to n funni lai gb'ebo ooo
ope la mu wa
KO si oo
KO si ooo
KO si oo
KO si leyin re
KO si oo
KO si oo
KO si oo
KO si leyin re
alagbara kan KO ma si
onimo kan KO ma ma si oo
KO si oooo
KO si leyin re
Iwo ni n o ma yin lojojumo
Iwo ni maa f'aye mi gbe gaooo
KO s'elomiran leyin re
KO si oooeee
KO si o
KO si o
KO si o
KO si leyin reko si o
KO si o
KO si o
KO si o
KO si leyin re
KO si o
KO si o
KO si o
KO si leyin re
KO si o
KO si o
KO si oo
KO si leyin re
ko si o
ko si o
KO si o
KO si leyin re