![Ma Je Nsina](https://source.boomplaymusic.com/group2/M00/01/2F/rBEeNFfyCemACFc4AADHzuhFQfQ826.jpg)
Ma Je Nsina Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2015
Lyrics
Ma je nsina ni mo wi
Ma je nsina ni mo toro
Ma je nsina ni mo wi
Ma je nsina ni mo toro
Mo mo bi mo duro ti o o ire ni
Mo mo bi mo sogo ninu re ola ni
Igbeyin mi ko to ko ju ibeere mi lo
Ki ma pa da wa rin gbe o oluto ise mi
Ibeere mi ko da kin ki igbeyin mi ma baje o
Kin ma fi beere si wa wu o olu pe to pe mi
Ma je nsina ni mo wi
Ma je nsina ni mo toro
Ma je nsina ni mo wi
Ma je nsina ni mo toro
Aiye ti ri mi pe odo re ni mo tedo si
Won ni kin wa mo ba ko jale pe o to fun mi
Aiye ri mi pe odo re ni mo tedo si
Won ni kin wa mo ba refuse pe oto fun mi
Ibi ikoko re ni mo ba si o dodo
Abe ojiji re ni mo gbe tile tile
Iwo ni abo mi ati asa mi
Mo koja aye mi ibi oran mi ni mo duro si
Bi ba tin se ife re abu shey bu shey
Tu bo ma to mi ko de gbami lowo aiye
Ma je nsina ni mo wi
Ma je nsina ni mo toro
Ma je nsina ni mo wi
Ma je nsina ni mo toro
Aiye ti ri mi pe odo re ni mo tedo si
Won ni kin wa mo ba ko jale pe o to fun mi
Aiye ri mi pe odo re ni mo tedo si
Won ni kin wa mo ba refuse pe oto fun mi
Ibi ikoko re ni mo ba si o dodo
Abe ojiji re ni mo gbe tile tile
Iwo ni abo mi ati asa mi
Mo koja aye mi ibi oran mi ni mo duro si
Bi ba tin se ife re abu shey bu shey
Tu bo ma to mi ko de gbami lowo aiyeeeeeeee
Ma je nsina ni mo wi
Ma je nsina ni mo toro
Ma je nsina ni mo wi
Ma je nsina ni mo toro
Ma je nsina ni mo wi
Ma je nsina ni mo toro
Ma je nsina Aminnnnnnnnnn