![Ife](https://source.boomplaymusic.com/group1/M00/01/32/rBEeMlfyE6GATyyOAADwesOXwoM426.jpg)
Ife Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2014
Lyrics
Ife - Sola Allyson Obaniyi
...
***Instrumental***
Ba mi so tito
Mo fe o tooto
Ba mi so dodo
Mo fe o pelu ododo
Ba mi so tito
Ololufe mo fe o tooto
Ba mi so dodo
Mo fe o pelu ododo
Bo ogiri oba lanu alangba ole wo ogiri (2x
Eledaa lo yaan wa paapo
Esu koni yaa wa o
Ife bi eji owuro
La ti agbala Eledumare loti se waa
Ife to tooro mini mini
Ta bo awon aye kan o le baje o
Ololufe feranmi lai se etan
Ife bi eji owuro
Lati agbala Eledumare loti se waa
Ife to tooro mini
Ta bo awon aye kan o le baje o
Ore okan mi feran mi lai se etan
Fe mi bi oju ti n fe imu
Fe mi bi irun ti n fe ori
Fe mi bi eyin ti n fe nu
Fe mi temi temi
Fe mi tokantokan
Fe mi tara tara
Ololufe feran mi lai se etan o
Fe mi bi oju ti n fe imu
Fe mi bi irun ti n fe ori
Fe mi bi eyin ti n fe nu
Fe mi temi temi
Fe mi tokantokan
Fe mi tara tara
Ololufe feran mi lai se etan o
*** Instrumental***
Duro ti mi o ololufe
ife ti ko labukun ni ko bami lo
Duro timi o ololufe
ife ti ko labawon ni ko bami lo
Ife bi eji owuro
La ti agbala Eledumare loti se waa
Ife to tooro mini mini
Ta bo awon aye kan o le baje o
Ololufe feranmi(feranmi) lai se etan
Fe mi bi oju ti n fe imu
Fe mi bi irun ti n fe ori
Fe mi bi eyin ti n fe enu
Fe mi temi temi
Fe mi tokan tokan
Fe mi tara tara
Ololufe feran mi lai se etan
Ama lowo lo wo
Ama bimo le mo
Ama shayo ma yo
Ama Shola mo la
Ka sha mu ife Eledumare se lai se etan
Ife bi eji owuro
La ti agbala Eledumare loti se waa
Ife to tooro mini mini
Ta bo awon aye kan o le baje o
Ololufe feranmi lai se etan
Ife bi eji owuro
La ti agbala Eledumare loti se waa
Ife to tooro mini mini
Ta bo awon aye kan o le baje o
Ololufe feranmi feranmi feranmi
Gba imoran mi ololufe mi
Oluranlowo la fi mi se fun o
Latorun wa
Feti si amoran mi Ayanmo wa jo ra won
Oluranlowo la fi mi se fun o
Latorun wa
Ka jo rin
ka s'okan gbe oruko olorun
A la ba rin la fimi se fun o
Latorun wa
Mokan kuro ninu Asan aye
Etan o daa nkan kan fun ni
Ife ati ope lo le muwa la aye ja lai laba won
Mokan kuro nini asan aye
Etan o daa nkan kan fun ni
Ife ati ope lo le mu wa la aye ja lai laba won
Ife bi eji owuro
La ti agbala Eledumare loti se waa
Ife to tooro mini mini
Ta bo awon aye kan o le baje o
Ololufe feranmi lai se etan
Ife bi eji owuro
La ti agbala Eledumare loti se waa
Ife to tooro mini mini
Ta bo awon aye kan o le baje o
Ololufe feranmi lai se etan
Duro timi o ololufe
Ife ti ko labawon ni ko bami lo
Duro timi o ololufe
Ife ti ko letan rara ni ko bami lo
Duro ti mi o ololufe
ife ti ko labukun ni ko bami lo
Duro ti mi o ololufe
Ife ti ko labukun ni ko bami lo
Duro ti mi o ololufe
ife ti ko labukun ni ko ba mi lo
*Ends*