Ki Ijoba Re De Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2023
Lyrics
Je ki'joba re de
Kristi k'asee re bere
Je ki'joba re de e
ki gbogbo aye le mo o
Won tun mbe won si po
Aborisa tun po o
Awon ti o bo loju gbamgba
Won mborisa ni ikoko
Igbiyanju lati pe won wa
Sinu agbo re
Won gan nsa ipa ti won ni
Lati po si ninu agbo won
Won nse eyi o baba
Toripe won ko mo o
Won nse eyi o baba
Toripe won o da o mo
Okunkun bo'le sibe ni
Ile e keferi, dide irawo oroo
Dide mase wo mo oo (Je ko de)
Won tun mbe won si wa
Alagbere tun wa o, pansaga
Eke, onirera, omuti o mo niwon Egbefa, igbiyanju lati pe won wa
Sinu agbo re, awon gan nsa
Ipa ti won ni
Lati wa enia kun ara won
Won nse eyi o baba
Won ro'pe o ti lo patapata
Won nse eyi o baba
Won ro'pe o ko nii de mo
Akoko na ha da, t'ote yi o pari
Ika ati'reje, pelu ifekufe (gbawa o)
Won tun mbe won si wa
Awon olufe ija at'ogun
Ko si ifokanbale kankan
Lori'leede yi o, bere lati'nu ile
Ogun ninu ijo Olorun
Ka to so ti'nu ilu kookan
Titi fi de t'orileede
Igbawo niii ife yo ha j'ob
Wonwonyi to'ju su wa
Alade iye gbawa o
Ani ijoba ife da? ati t'alafia
Gbawo ni irira gbogbo
Yi o tan bii t'orun (gbawa o)