- Genre:Gospel
- Year of Release:2023
Lyrics
Ina, ina wonu mi o
Ina wonu mi oo, oo, k'agbara de
Ina, ina wo'nu mi o
Ina wo'nu mi oo, oo
Ki n di alagbara
Loni o, oo, mo wo'nu mi wo o
Mori iwa ese ati t'esu
Ti o je nmi'imi iye, igberaga
Ote ipaniyan ati bee bee lo
Oro Re ye o, ida oloju meji ni
Okan mi gb'ogbe
Mo fe gbalejo ara o
Ina wo'nu mi ooo
Ki n di alagbara
Ina, ina wo'nu mi ooo
Jesu oo, oo, wa wo ijo re
Esu lo n waasu
Ole lo n ko'wo lowoasewo
Lo n korin afose lon gbadura
Itan lasan lokuhaaaaa
Ina ti ku, okan wa gb'ogbe
A fe gbalejo ara o
ina wo'nu ijo ooo
kaa di alagbara
ina, ina wo'nu mi ooo
Isoji mo pe oo, mo pe
Ko wa bere oo, isoji ina bere oo
Bere lati'nu mi
Emi mimo ni mo fe
Emi alagbara
Wo'nu mi ooo ki n di alagbara Igbagbo to ti ku, egungun to ti D'egbe, e gba iye ooo
Ina Oluwa de eeee
Ina, ina wo'nu mi ooo
Mighty, Mighty, Mighty, Mighty
Holy, holy, holy, holy ghost fire
Holy, holy, holy, holy ghost fire
Ina, ina wo'nu mi ooo