Agbelebu Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2023
Lyrics
Agbelebu
by Oluwaseun Teerinteerin
Aagbelebu ti mo mo agbara ni, igba mo gbe e, gbogbo kirakita mi tan, aagbelebu la kan ese mi mo, aagbelebu lo funmi n'ireti orun.
1. Aye mi tele kun fun iya, ese, at'ise, mo ma teriba labe agbelebu, a darijimi, a pa ese mi re, aagbelebu la kan ese mi mo, aagbelebu lo funmi n'ireti orun.
Chorus: Aagbelebu ti mo mo.....
2. Adagun Omi, se e mo b'o se riri to, idoti lotun Ogun losi bee ni mo ri, mo jewoo Jesu, a si kan mi mo'gi, aye mi di mimo ngba ta f'eje we mi, aagbelebu la kan ese mi mo, aagbelebu lo funmi n'ireti orun.
Chorus: Aagbelebu ti mo mo agbara ni.......
3. Mo di ti Jesu l'ojo na, mo yege, O somi di titun mgba mo gba lati tele, mo gbagbe iya, iya ese to to Simi, ati p'ojo gbogbo ni mo ngb'agbelebu, egun at'eran'ara ko si jobaa mi mo, aagbelebu la Kan ese mi mo, aagbelebu lo funmi n'ireti orun.
Call: Ni jijewo Resp: Ka jewoo Re o Jesu.
Call: Siseraeni Resp: Ka seraeni.
Ka ko ese sile, Ka maa reti ojo ologo, eyi ni mo mo ti a fi ngb'agbelebu.
Chorus: Aagbelebu ti mo mo agbara ni........