Mò Sí Nú Lyrics
- Genre:Afropop
- Year of Release:2023
Lyrics
Mò Sí Nú - leemong
...
Eh eh eh eh eh
Ma rò fun won
Òrò pò níkùn mió
Amó eyí obawùmi ní maso
Bé beré dola
Eyi oba wùmi miò niwi
Bè bere dólá
Ma fówó luwò bi odí Ni
Ah
Eníyań masòrò oh
Bòwí fùn won padé guń
Won áni opè koma gun o
Ah mobèru eyan
Ásoro Ana di bámi
Kójù otò moń
Kójó oto mon oh
Mòsínú mósikun re oré
Bá'núso Ma Beníyań so
Mòsínú mósikun re oré
Bá'núso Ma Beníyań so
Dakun
Ma ma béniyań só
Ma ma béniyań só
Bá’núso Ore!
Bá’núso Ore!
Bòre damì komolé dunmì
Motiri Abínìbí tińdani
Tiń sè eh moń rojò fuń ikà
Moń rojò mi fú Alaìda
Ibí enù dé É-se ode be
Mò to pò mó
Semí nbì éh lòrén dùn
Tin bá se éh pèmi oshò
Márojo mi fùn wòn
Màrojo mi fùn wòn
Mòsínú mósikun re oré
Bá'núso Ma Beníyań so
Mòsínú mósikun re oré
Bá'núso Ma Beníyań so
Dakun
Ma ma béniyań só
Ma ma béniyań só
Bá’núso Ore!
Bá’núso Ore!