MIMO MIMO MIMO Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2022
Lyrics
Mimo, mimo , mimo, Olodumare Lojojumo, wo ogbo orin wa
Ologo meta, lai Olubukun
Mimo, mimo, mimo, oniyonu julo
Kabiyesi o, a juba re
Oba awon oba, ajuba re
Iyin re ni yo ma wa lenu, awa ayanfe
Mimo, mimo, mimo, awon torun yin Won fi ade wura won, lele yi teka Cherub, Seraphim, wo le, ni a ju re Wo to ti wa, to si wati ti, lai ati lai lai
Mimo, mimo, mimo, bokunkun pa omo Bo ju else, koleri ogo re
Wo ni ikan lomo, ko se lomiran
Pipe ninu agbara ati nife
Mimo, mimo mimo, Olodumare Gbogbo ise re, nile lonyin o
Ologo meta, lai Olubunkun Mimo, mimo, mimo
Oniyonu julo