GBO GBO AYE Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2022
Lyrics
GbogboayegbeJesuga Angeli ewole fun Baba
E mu ade oba re wa
See ni oba, awon Oba Ese loba eyin martyr
Tin gbe ni pepe Baba Gbe gbogbo igi Jese ga Ese ni Oba, awon oba
Halleluhah, orin to dun ni
Halleluyah, orin didun ni
Halleluyah, orin isegun
Tawa ta ti rapada O Yes
Tawa ta ti dariji O Yes
Haaa, Halleluyah, Halleluyah yin Baba
Kigbogboorileede
Ni gbogbo agbaye, gbe ga Ki won ki Kabiyesi
See ni oba, awon oba Abale pe lawon torun
Lati ma juba Baba
Kabale jumo korin
See ni oba, awon Baba