MA BERU Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2022
Lyrics
Ma beru emi ti ra o pada Ma foya
Temi ni iwo nse e Ma beru mow a pelu re
Gbati won ban la omi koja unopelureo
Ati laa rin odo ki yo bo o mole o
Gbati wo banrin ninu ina
Ina ki yo jo o oo
Be ni mowi owo in ki yo ran o rara oooo
Nitori emi ni Oluwa Olorun Israeliooo
Iwoseiyebiye emisifeoooo
E mi o wi fun ari wa pe I o da sile oooo
Ati fun Gusu pe ko ma se dawo duro ooo Nitoripe
Emi ti da o fun ogo mi ooo Nitori emi ni Oluwa Olorun Isrealiooo
Iwonielerimi atiiransetimoyan
Ki wo ki ole momi kosi le gba mi gbo ooo Ki o si ye o pe
Ko s Olorun sha ju mi ooo Beni mo wi Ko si lesi Olorun
Kan leyin mi o Nitori emi ni Oluwa Olorun Israeli oo
Emiyoseohuntitunninuayereoo
Emi yi o la ona ninun aginju ooooooo
Omi yi o sun jade ninu ashale ooo
Lati fohun mimun fun awon ayange
Mimun Nitori emi ni Oluwa
Olorun Isrealioooooo