Igba Otun Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2022
Lyrics
Igba to wo le yi o
Igba otun ni
Igba to wo le yi o
Igba otun ni
Ko ma si confusion
Igba otun ni o
Igba otun ni
Igba to wo le yi o
Igba otun ni
Igba to wo le yi o
Igba otun ni
Ko ma si confusion
Igba otun ni o
Igba otun ni
New era new era
Igba otun de
Igba otun de
Igba otun de o
Just like that
Igba to wo le yi o
Igba otun ni
Igba otun ni
Igba to wo le yi o
Igba otun ni
Igba otun ni
Ko ma si confusion
Igba otun ni o
Igba otun ni
New era new era
Igba otun de
Igba otun de
Igba otun de o
Just like that
Igba otun de
Igba otun de
Igba otun de o
Just like that
Igba to wo le yi o
Igba otun ni
Igba to wo le yi o
Igba otun ni
Igba to dara
Ko ma si confusion
Igba otun ni o
Igba otun ni
Iwe mimo so wi pe
Teda bati wa ninu jesu
Oti dotun
Iwe mimo so wi pe
Teda bati wa ninu jesu
Oti dotun
Igba to wo le yi o
Igba otun ni
Igba otun ni
Igba to wo le yi o
Igba otun ni
Igba otun ni
Ko ma si confusion
Igba otun ni o
Igba otun ni
Emi tiwa datunbi ninu jesu
Moti dotun
Emi tiwa datunbi ninu jesu
Moti dotun
Igba to wo le yi o
Igba otun ni
Igba otun ni
Igba to wo le yi o
Igba otun ni
Igba otun ni
Ko ma si confusion
Igba otun ni o
Igba otun ni
Wash in the blood of the lamb
Ko di tun tun
Wash in the blood of the lamb
Ko di tun tun
Wash in the blood of the lamb
Ko di tun tun
Wash in the blood of the lamb
Ko di tun tun
Igba to wo le yi o
Igba otun ni
Igba otun ni
Igba to wo le yi o
Igba otun ni
Igba otun ni
Ko ma si confusion
Igba otun ni o
Igba otun ni
Mo ti layo ninu jesu halleluyah
Oba mimo lo fi fe ra mi pada
Titi aiye lemi oma kalleluyah
Halleluyah soba mi ologo
Mo ti layo ninu jesu halleluyah
Oba mimo lo fi fe ra mi pada
Titi aiye lemi oma kalleluyah
Halleluyah soba mi ologo
Igba to wo le yi o
Igba otun ni
Igba otun ni
Igba to wo le yi o
Igba otun ni
Igba otun ni
Ko ma si confusion
Igba otun ni o
Igba otun ni
Kilonsoni dotun o
Kilonsoni dotun
Iwa mimo
Ise mimo
Bi ti jesu
Lonsoni dotun
Kilonsoni dotun o
Kilonsoni dotun
Iwa mimo
Ise mimo
Bi ti jesu
Lonsoni dotun
E yi ni jesu fe fun araye
Iwa mimo ninu ife
Eyini jesu fe feda eniyan
Iwa mimo ninu ododo
Igba to wo le yi o
Igba otun ni
Igba otun ni
Igba to wo le yi o
Igba otun ni
Igba otun ni
Ko ma si confusion
Igba otun ni o
Igba otun ni
Igba to wo le yi o
Igba otun ni
Igba otun ni
Igba to wo le yi o
Igba otun ni
Igba otun ni
Ko ma si confusion
Igba otun ni o
Igba otun ni
Mo sasaro lokan mi o
O ti je ki n mo o
Baba kodoju timi o
Mo sasaro lokan mi o
O ti je ki n mo o
Baba kodoju timi o
Mo sasaro lokan mi o
O ti je ki n mo o
Baba kodoju timi o
Mo sasaro lokan mi o
O ti je ki n mo o
Baba kodoju timi o
Wiwa ti mowa laiye o
Agbara mi ko rara
Baba mi lo gbe Ida soke
O fija fun mi
Wiwa ti mowa laiye o
Agbara mi ko rara
Baba mi lo gbe Ida soke
Ofi ja funmi
Mo sasaro lokan mi o
O ti je ki n mo o
Baba kodoju timi o
Mo sasaro lokan mi o
O ti je ki n mo o
Baba kodoju timi o
Ijo le mi o ma jo
E rin le mi o ma rin
Edumare ti se mi logo
E wa ba mi yo
Mo sasaro lokan mi o
O ti je ki n mo o
Baba kodoju timi o
Mo sasaro
Mo sasaro lokan mi o
O ti je ki n mo o
Baba kodoju timi o
Akobi eledumare
Tewo gbopemi
Akobi eledumare
Tewo gbopemi
Akobi eledumare
Tewo gbopemi
Akobi eledumare
Tewo gbopemi
Bi mo ba ji lo wuro
Ma mope mi wa
Akobi eledumare
Tewo gbopemi
Bi mo ba ji lo wuro
Ma mope mi wa
Akobi eledumare
Tewo gbope mi
Ai monu ro
Oun lai mope du rara
Akobi eledumare
Tewo gbopemi
Ai monu ro
Oun lai mope du rara
Akobi eledumare
Tewo gbopemi
Titi aiye lope mi lodo re baba
Akobi eledumare
Tewo gbope mi
Titi aiye lope mi lodo re baba
Akobi eledumare
Tewo gbope mi
Mo sasaro lokan mi o
O ti je ki n mo o
Baba kodoju timi o
Mo sasaro lokan mi o
O ti je ki n mo o
Baba kodoju timi o
Mo sasaro lokan mi o
O ti je ki n mo o
Baba kodoju timi o
It is great to be greatful to God
It is great to be greatful to God
It is great to be greatful to God
It is great to be greatful to God
I am greatful to God
I am greatful in heart
It is great to be greatful to God
I am greatful to God
I am greatful in heart
It is great to be greatful to God
Mo sasaro lokan mi o
O ti je ki n mo o
Baba kodoju timi o
Mo sasaro
Mo sasaro lokan mi o
O ti je ki n mo o
Baba kodoju timi o