![Oruko Jesu](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/10/12/118d69c2c99e43deaba7c71c12e8e076_464_464.jpg)
Oruko Jesu Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2022
Lyrics
Oruko jesu yii o
A a pata lo je o
Pon bele
Mo du ro le
Oruko yii apata
Apata
Mo duro le
Oruko yii apata
Apata
Mo duro le oruko yii apata
Apata
Mo duro le
Oruko yii
Oruko jesu yii o
A a pata lo je o
Pon bele
Mo du ro le
Oruko yii apata
Apata
Mo duro le
Oruko yii apata
Apata
Mo duro le oruko yii apata
Apata
Mo duro le
Oruko yii
Gbogbo oruko to wa laye
Oruko jesu o ta won yo
Oun lomu ibanuje tan
Oun lotun foyin saiye eeni
Nigba ti ota ba gbogun de
Abo lo je o
Lo jo iponju
Oruko jesu yii o
A a pata lo je o
Pon bele
Mo du ro le
Oruko yii apata
Apata
Mo duro le
Oruko yii apata
Apata
Mo duro le oruko yii apata
Apata
Mo duro le
Oruko yii
Igbagbo ti mo ni o
O duro lori apata o pon bele
Igbagbo ti mo ni o
O duro lori apata o pon bele
Gbogbo oruko to wa laye
Oruko jesu o ta won yo
Oun lomu ibanuje tan
Oun lotun foyin saiye eeni
Nigba ti ota ba gbogun de
Abo lo je o
Lo jo iponju
Oruko jesu yii o
A a pata lo je o
Pon bele
Mo du ro le
Oruko yii apata
Apata
Mo duro le
Oruko yii apata
Apata
Mo duro le oruko yii apata
Apata
Mo duro le
Oruko yii
Mo ti wa mo wi pe
Gbogbo oruko to lodi soruko yii o
Iyanrin ni
Mo ti wa mo wi pe
Gbogbo oruko to lodi soruko yii o
Iyanrin ni
Gbogbo oruko to wa laye
Oruko jesu o ta won yo
Oun lomu banuje tan
Oun lotun foyin saiye eeni
Nigba ti ota ba gbogun de
Abo lo je o
Lo jo iponju
Oruko jesu yii o
A a pata lo je o
Pon bele
Mo du ro le
Oruko yii apata
Apata
Mo duro le
Oruko yii apata
Apata
Mo duro le oruko yii apata
Apata
Mo duro le
Oruko yii
Emi ko beru ibi kan
Mo ni igbagbo ninu oruko baba
Emi ko beru ibi kan
Mo ni igbagbo ninu oruko baba
Gbogbo oruko to wa laye
Oruko jesu o ta won yo
O un lo mu banuje tan
O un lotun foyin saiye eeni
Nigba ti ota ba gbogun de
Abo lo je o
Lo jo iponju
Oruko jesu yii o
A a pata lo je o
Pon bele
Moduro le oruko yii apata
Apata
Mo duro le oruko yii apata
Apata
Mo duro le oruko yii apata
Apata
Mo duro le oruko yii
Mo duro le oruko yii apata
Apata
Mo duro le oruko yii apata
Apata
Mo duro le oruko yii apata
Apata
Mo duro le oruko yii
Mo duro le oruko yii apata
Apata
Mo duro le oruko yii apata
Apata
Mo duro le oruko yii apata
Apata
Mo duro le oruko yii