Alujanjankijan ft. Adekunle Gold Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2017
Lyrics
Alujanjankijan ft. Adekunle Gold - Sola Allyson Obaniyi
...
Iya iya ta kun wa le
(Alujanjankijan)
Iya Iya ta kun wa le
(Alujanjankijan)
E ma fi omo si le fun iyaje
(Alujanjankijan)
E ni to bi omo lo ye ko wo omo
(Alujanjankijan)
Ba mi na omo mi o ye ko de nu olomo
O ju merin lo bi omo sugbon lgba oju ni wo omo
Omo ta ko agbe le ta ko ta
Omo ta to ake esho ta ni ta
Omo ni gbeyin omo lola
Omo lola omo ni yin
Omo lade omo lewa
Omo lesho ooooooo
Oda bi o da ole da
Osan bi o san a de san
Igboya ati adura ni ogba yi o daaaa
Iya Iya ta kun wa le
(Alujanjankijan)
Iya Iya ta kun wa le
(Alujanjanjkijan)
E ma fi omo si le fun iyaje
(Alujanjankijan)
E ni to bi omo lo ye ko wo omo eto omo
(Alujanjankijan)
Ori fun wa lomo rere bi ti Samueli o
Wan ko Samu ogbe ko o si seun re
If you spare the rod you go spoil the child
I hope you know
Train dem with the love of God i beg o
Tori alai gboran omo
(Ashani)
Agba oku won loju
(Ashani)
Agba o jo won lo ju
(Ashani)
Agbaya ni o da
(Ashani)
Alai gboran omo
(Omo ni)
Wan de ni yan lola
(Omo ni)
Ta ba to wan dada o
(Omo ni)
Won de ni yan lola
Iya Iya ta kun wa le
(Alujanjankijan)
Iya Iya ta kun wa le
(Alujanjankijan)
E ni to bi omo lo ye ko wo omo
(Alujanjankijan)
E ma fi omo si le fun iyaje
(Alujanjankijan)
Iya Iya ta kun wa le
(Alujanjankijan)
E ma fi omo si le fun iyaje
(Alujanjankijan)
E ni to bi omo e lo ye ko wo omo e eto wan
(Alujanjankijan)
Iya mama ta kun wa le o
(Alujanjankijan)
Kekere lan tin peka iroko to ba dagba tan ebo ni o ma gba
Owun taba fi sile lewure n gbe
Ke wure aiye ma ma gbe wa lomo lo
Omo ta ba to ekun aiye agbe lo
Ke kun aiye ma ma gbe wa lomo lo
Iya Iya ta kun wa le
(Alujanjankijan)
Iya Iya ta kun wa le
(Alujanjankijan)
Iya Iya ta aaaaaaaaaa
(Alujanjankijan)
Iya Iya ta kun wa le ooo
(Alujanjankijan)
Edumare ko ba wa to omo wa o
(Alujanjankijan)
Edumare ko ba wa to omo wa
(Alujanjankijan)
Children are the heritage of the Lord o
(Alujanjankijan)
Egbo omo lola
Omo lade omo lewa omo lere
Ka fa ye si le ka to omo wa o
(Alujanjankijan)
They are the future generation
(Alujanjankijan)
Iya Iya ta kun wa le
(Alujanjankijan)